Michael Bloomberg
Olóṣèlú
Michael Rubens Bloomberg[2] tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kejì ọdún 1942 (February 14, 1942) jẹ́ pàràkòyí olóṣèlú, oníṣòwò àti oǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Òun ni Aláṣẹ àti ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ Bloomberg L.P., Bloomberg ni Alákòóso Ìlú-ńlá New York láti ọdún 2002 sí 2013. Lọ́wọ́ báyìí, òun ní adíje dùpò Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Democratic Party tí yóò wáyé lọ́dún 2020.[3]
Michael Bloomberg | |
---|---|
108th Alákòóso Ìlú-ńlá New York | |
In office January 1, 2002 – December 31, 2013 | |
Deputy | Patricia Harris |
Asíwájú | Rudy Giuliani |
Arọ́pò | Bill de Blasio |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Michael Rubens Bloomberg 14 Oṣù Kejì 1942 Boston, Massachusetts, U.S. |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic (kí ó tó di 2001, 2018–títí di àkókò yìí) |
Other political affiliations | Independent (2007–2018) Republican (2001–2007) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Susan Brown-Meyer (m. 1975; div. 1993) |
Domestic partner | Diana Taylor (2000–àkókò yìí |
Àwọn ọmọ | 2, including Georgina |
Education | Johns Hopkins University (BS) Harvard University (MBA) |
Net worth | US$61.8 billion (February 2020)[1] |
Signature | |
Website | Official website |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Michael Bloomberg". Forbes. https://www.forbes.com/profile/michael-bloomberg.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:7
- ↑ Burns, Alexander (November 24, 2019). "Michael Bloomberg Joins 2020 Democratic Field for President". New York Times. https://www.nytimes.com/2019/11/24/us/politics/michael-bloomberg-2020-presidency.html.