Michelle Marie Pfeiffer ( /ˈffər/; tí a bí ní oṣù kẹrin ọjọ́ ọ̀kàn-dín-lọ́gbọ̀n, ọdún 1958) jẹ́ òṣèré ará Ilẹ̀ Amẹ́ríkà kan. Òṣèré tí ó ní ìlọsíwájú tí iṣẹ́ ìbòjú rẹ̀ ti kọjá ogójì ọdún, ó di ọ̀kan nínú àwọn òṣèré Hollywood tó jẹ́ àkọṣẹ́mọṣẹ́ tó dùn yàtọ̀ jùlọ ní àwọn ọdún 1980 àti 1990, bákan náà ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn àmì ìbálòpọ̀ olókìkí jùlọ ti àkókò náà. Olùgbà ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àmì ìyìn, ó ti gba Ààmì Ẹ̀yẹ Golden Globe kan àti Ààmì Ẹ̀yẹ British Academy Film kan, ní àfikún sí àwọn yíyán fún àwọn Ààmì Ẹ̀yẹ Academy mẹ́ta àti Ààmì Ẹ̀yẹ Primetime Emmy kan. Ní ọdún 2007, wọ́n fún un ní ìràwọ̀ àwòrán fíìmù kan lórí Hollywood Walk of Fame.

Michelle Pfeiffer
Pfeiffer at the premiere of Stardust in 2007
Ọjọ́ìbíMichelle Marie Pfeiffer
Oṣù Kẹrin 29, 1958 (1958-04-29) (ọmọ ọdún 65)
Santa Ana, California, U.S.
Orílẹ̀-èdèAmerican
Iṣẹ́
  • Actress
  • producer
Ìgbà iṣẹ́1978–present
Olólùfẹ́
Peter Horton
(m. 1981; div. 1988)

David E. Kelley (m. 1993)
Àwọn ọmọ2
ẸbíDedee Pfeiffer (sister)
AwardsFull list
Websiteinstagram.com/michellepfeifferofficial


Itokasi àtúnṣe