Mide Martins
Mide Funmi Martins jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, àwòṣe àti aṣàgbéjáde eré. Ó jẹ́ ọmọ òṣèrébìnrin Funmi Martins, tí ó kú nípa àrùn ọkàn ní ọdún 2002.[1][2][3][4]
Mide Martins | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Mide Funmi Martins Lagos Island, Lagos State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Olabisi Onabanjo University |
Iṣẹ́ | |
Ìgbà iṣẹ́ | 2002–present |
Gbajúmọ̀ fún | ku Orun |
Olólùfẹ́ | Afeez Owo |
Àwọn ọmọ | 2 |
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeMide Martins bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ lẹ́yìn ikú ìyá rẹ̀ ní ọdún 2002.[5] Láti ìgbà náà, ó ṣe àfihàn nínú fíìmù àgbéléwò lóríṣiríṣi, ó sì ṣàgbéjáde àwọn ère lóríṣiríṣi.
Ìgbésí ayé rẹ̀
àtúnṣeMide Martins jẹ́ ọmọ Funmi Martins. Orúkọ ọkọ rẹ̀ ń jẹ́ Afeez Owo, ó sì bí àwọn ọmọ méjì fún un.[6][7]
Àtòjọ àwọn eré rẹ̀
àtúnṣeÀwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "My husband has never raised his hand against me — Mide Martins". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-10-16. Retrieved 2022-07-16.
- ↑ "How I saved my marriage– Mide Martins-Abiodun". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-07-31. Retrieved 2022-07-16.
- ↑ "Mide Martins: Filmmaking is more than making money The Nation Newspaper" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-04-02. Retrieved 2022-07-16.
- ↑ "Nollywood actress Mide Martins suffers head injury (Video) - P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-16.
- ↑ Ngwan, Nenpan (2021-06-29). "Mide Martins Biography and Age Accomplishments as a Yoruba Actress". BuzzNigeria.com. Retrieved 2023-03-07.
- ↑ "Mide Martins, husband Afeez Owo celebrate 17th wedding anniversary - P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-16.
- ↑ "Mide Martins Biography (Early Life, Family, Career)". Naijabiography Media. 2022-04-25. Retrieved 2023-03-07.
- ↑ "Mide Funmi Martins". IMDb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-23.
- ↑ Aderemi, Samson (2022-08-19). "Odunlade and Mide Martins in an all action latest yoruba movie –Iyawo Buga". iBrandTV (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-23.