Michael Oladapo Afolarin (tí a bí ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹsàn-án) ti orúkọ oníṣẹ́ rẹ̀ jẹ́ Mike Afolarin jẹ́ òṣèrékùnrin orílẹ̀-èdẹ̀ Nàìjíríà, ayàwòrán àti olúṣe fíìmù.[1]

Mike Afolarin
ÌbíLagos State, Nigeria
Iṣẹ́
  • Actor
  • filmmaker

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Mike Afolarin lọ sí ilé-ìwé Federal Government College, Ijanikin, Lagos State fún ẹ̀kọ́ girama rẹ̀. Ó tẹ̀síwájú láti gboyè bachelor’s degree ninú ẹ̀kọ́ tó papọ̀ mọ́ ètò ìṣúná ní University of Lagos (UNILAG) ní ọdún 2016.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. TOPCHARTS (2024-02-13). "Mike Afolarin: Nollywood Superstar". Top Charts Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-07-02. 
  2. Famuwagun, Olamide (2023-01-17). "How school strike drove me into acting – Mike Afolarin". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-07-02.