Miliky MiCool
Òṣèrẹ́bìnrin ilè Ghana
(Àtúnjúwe láti Miliky cool)
Beatrice Chinery tí ọ̀pọ̀ è Miliky MiCool (c. 1966 – June 10, 2020) jẹ́ òṣèrébìnrin ilẹ̀ Ghana. Ó di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tí ó kópa nínú fíìmù kan ní ọdún 2000, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Kejetia, lẹ́yìn náà ló ṣàfihàn nínú Yolo.[1]
Miliky MiCool | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Beatrice Chinery 1966 |
Aláìsí | June 10, 2020 Accra |
Orílẹ̀-èdè | Ghanskaian |
Iṣẹ́ | actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1966 - 2020 |
Notable work | Yolo |
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
àtúnṣeÓ bẹ̀rẹ̀ isẹ́ fíìmù ṣíṣe ní ọdún 1993. MiCool kópa nínú fíìmù Kejetia ní ọdún 2000. Lẹ́yìn náà ni ó kópa nínú àwọn fíìmù bí i Jamestown Fisherman àti Yolo.[1][2][3]
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
àtúnṣe- Kejetia
- Yolo
- Jamestown Fisherman
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Ghanaian actress Miliki Micool of 'Kejetia' TV series fame dies". Citinewsroom - Comprehensive News in Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-06-11. Retrieved 2020-06-12.
- ↑ Online, Peace FM. "Ghanaian Actress Beatrice Chinery A.k.a 'Miliky MiCool' Has Died". Peacefmonline.com - Ghana news. Archived from the original on 2022-11-22. Retrieved 2020-06-10.
- ↑ ""James Town Fisherman TV series has come to stay"". www.ghanaweb.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-09-16. Retrieved 2020-06-12.