Mimi Fawaz jẹ́ akọròyìn eléré ìdárayá tí ilẹ̀ Nàìjìríà-Labanese, olùdarí ètò àti olóòtú tí ó ń ṣiṣẹ́ gẹgẹ́ bíi olóòtú eré ìdárayá ní focus on Africa,tí ìròyìn BBC ifètòlède fún BBC World News pẹ̀lú BBC Africa àti BBC Sports. Ó ti ṣiṣẹ́ fún CNN, ESPN àti ITV Television Network.[1][2][3][4] Ní oṣù kìíní ọdún 2017, ó darí ètò ọdún 2016 tí GLO-CAF Awards òun pẹ̀lú òsèré ìlú NàìjíríàRichard Mofe Damijo.

Mimi Fawaz
Iléẹ̀kọ́ gígaCity University of London
Iṣẹ́Sports journalist, Sportswriter
EmployerBBC World News, BBC Africa, BBC Sport.

Àwọn itokasi àtúnṣe

  1. Anchunda, Benly (13 August 2021). "2021 AFCON Draw: Your Co-host, Multiple Award Winning Mimi Fawaz". Cameroon Radio Television. Archived from the original on 13 August 2021. Retrieved 6 November 2021.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Mimi Fawaz and Richard Mofe-Damijo to emcee 2016 Glo-Caf Awards". CAFOnline.com. Confedération Africaine du Football (CAF). 4 January 2017. Retrieved 6 November 2021.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "MIMI FAWAZ Talks To Us about the Delight & Excitement She Gets Reporting on the Beautiful Game". Ytainment Arena. 19 January 2018. Archived from the original on 6 November 2021. Retrieved 6 November 2021.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "Mimi Fawaz – Journalist and sports presenter.". Performing Artiste. Retrieved 6 November 2021.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)