Mionga ki Ôbo (tàbí Mionga ki Ôbo: Mar e Selva) ni fíìmù ti ọdún 2002 kan tí wọ́n ṣe lórílẹ̀-èdè São Tomé and Príncipe, tí olùdarí rẹ̀ n ṣe Ângelo Torres [1] tí Luis Correia àti Noé Mendelle síì dì jọ ṣe àgbéjáde rẹ̀ láti ilé-iṣẹ́ LX Filmes.[2][3]

Mionga ki Ôbo
AdaríÂngelo Torres
Olùgbékalẹ̀Luis Correia
Noé Mendelle
Òǹkọ̀wéÂngelo Torres
OrinTiago Cerqueira
Ìyàwòrán sinimáDaniel Neves
OlóòtúVítor Alves
Ilé-iṣẹ́ fíìmùLX Filmes
Déètì àgbéjáde2005 (São Tomé and Príncipe)
Àkókò52 min.
Orílẹ̀-èdèSão Tomé and Príncipe
ÈdèPortuguese

Fíìmù náà dá lóri ìrìn-àjò àwọn olùgbé àtijọ́ ti erékùsù São Tomé tí wọ́n pè ní Angolares.[4] Wọ́n jẹ́ àwọn ìran Àngólà tí ó yè níbi jàmbá ọkọ̀ ojú-omi kan tí ó ṣẹlẹ̀ ní ọdún 1540.[5][6] Fíìmù náà jẹ́ ọ̀kan nínu àwọn fíìmù tí wọ́n gbéṣe gbogbo ètò rẹ̀ lórílẹ̀-èdè São Tomé and Príncipe.[7]

Àwọn olùkópa

àtúnṣe
  • Nezó as Himself - Painter, Musician, Sculptor
  • Vino Sr. as Himself - Retired Fisherman
  • João Sr. as Himself - Retired Fisherman
  • Baltazar Quaresma as Himself - Student
  • Julieta Paulina Lundi as Himself - Fisherman
  • Bibiano da Silva as Himself - Fisherman who no longer fishes
  • Fernando Sr. as Himself - Merchant
  • António Soares Pereira as Himself - Fisherman
  • Liga Liga as Himself - Healer
  • Dance Group of S. João dos Angolares as Themselves
  • Voice of the King Group as Themselves
  • Bulauê Group as Themselves
  • Congo Dance Group as Themselves
  • Anguené Group as Themselves

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Mionga ki ôbo". SPLA. Retrieved 21 October 2020. 
  2. "Mionga ki Ôbo: Mar e Selva". cinemaclock. Retrieved 21 October 2020. 
  3. "Mionga ki Ôbo - Mer et forêt Ângelo Torres". Africavivre. Tous droits réservés. Retrieved 21 October 2020. 
  4. "DVD – Mionga ki Ôbo, mar e selva". Librairie portugaise & brésilienne. Archived from the original on 26 October 2020. Retrieved 21 October 2020. 
  5. "Mionga ki Obo - mar e selva (2005): Mionga ki Obo - Sea and Jungle". African film database. Archived from the original on 26 October 2020. Retrieved 21 October 2020. 
  6. "Mionga ki Ôbo - Mer et forêt". filmaffinity. Retrieved 21 October 2020. 
  7. "Sea and the Jungle 2005 'Mionga ki Ôbo: Mar e Selva' Directed by Ângelo Torres". letterboxd. Retrieved 21 October 2020. 

Àwọn ìtakùn Ìjásóde

àtúnṣe