Mir (Rọ́síà: Мир, IPA: [ˈmʲir], Peace or World) ni ibudo-oko lofurufu to je ti Sofieti ko to di ti Rosia. Ohun ni o je ibudo lofurufu ibi isewadi akoko lagbaye ti awon eniyan gbe ninu re fun ojo pipe, o si tun je akoko iru iran eketa awon ibudo-oko lofurufu, won bere sii ko lati 1986 de 1996 pelu awoda modular. Ibudo oko yi sise fun odun medogun titi di March 23, 2001, nigbati won moomo mu kuro loju ona-iyipo re, ki o to ja si wewe ninu ipadawole si ojuorun lori Guusu Okun Pasifiki.

Mir
Mir following separation from the Space Shuttle Discovery, June 12, 1998
Mir insignia.
Station statistics
NSSDC ID:1986-017A
Call sign:Mir
Crew:3
Launch:1986–1996
Launch pad:LC-200/39, and LC-81/23, Baikonur Cosmodrome
LC-39A,
Kennedy Space Center
Reentry:2001-03-23
05:50:00 UTC
Mass:124,340 kg
(274,123 lbs)
Living volume:350 m³
Perigee:385 km (208 nmi)
Apogee:393 km (212 nmi)
Orbit inclination:51.6 degrees
Orbital period:88.15 minutes
Orbits per day:16.34
Days in orbit:5,519 days
Days occupied:4,592 days
Number of orbits:c.86,331
Statistics as of 04:57:10 UTC, March 23, 2001
References: [1]
Configuration
May 1996 configuration of Mir.




  1. "Mir-Orbit Data". Heavens-Above.com. March 23, 2001. Retrieved June 30, 2009.