Mizan Alem
Mizan Alem ni a bini keji leelogun, óṣu January ni ọdun 2002 jẹ elere sisa lobinrin ti ọna jinjin to gbajumọ ninu metres ti ẹgbẹrun marun ti órilẹ ede Ethiopia[1][2].
Òrọ̀ ẹni | |||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|
Ọjọ́ìbí | 22 January 2002 | ||||||
Sport | |||||||
Orílẹ̀-èdè | Ethiopia | ||||||
Erẹ́ìdárayá | Athletics (sport) | ||||||
Event(s) | long-distance running | ||||||
Achievements and titles | |||||||
Personal best(s) |
| ||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
|
Àṣèyọri
àtúnṣeNi ọdun 2021, Mizan gba ami ẹyẹ idanilọla ti gold ninu idije U20 ere sisa agbaye[3].
Itọkasi
àtúnṣe- ↑ "ALEM Mizan Records". Archived from the original on 2023-03-25. Retrieved 2023-03-25.
- ↑ Mizan Alem Profile
- ↑ Mizan Alem Wins Gold In U20 World Championships Women’s 5,000m