Mmabatho Montsho
Mmabatho Montsho (bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹwàá ọdún 1983) jẹ́ akọ̀wé, òṣèré àti adarí eré fíìmù) ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà.[1][2][3][4][5]
Wọ́n bíi sì ìlú Soweto. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Greenside High School kí ó tó tẹ̀ ṣíwájú sì ilẹ̀ ẹ̀kọ́ gíga tí University of South Africa níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò Audio-visual Multimedia. Ní ọdún 2006, ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe. Eré tí ó kọ́kọ́ ṣé ni A place called Home.[6] Ó gbà àmì ẹ̀yẹ Best Achievement in Script in a TV Drama láti ọ̀dọ̀ Golden Horn Award.[7] Ní ọdún 2020, ó gbà àmì ẹ̀yẹ fún eré ránpẹ́ tí ó dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ Worldwide Women's Film Festival.[8][9]
Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀
àtúnṣe- Jacob's Cross
- Happiness Is a Four-letter Word
- Artcha
- Mr Bones 2: Back from the Past as Wanita
- Plein Street
- Tempy Pushas as Noxy
- Nothing for Mahala
- Thula's Vine
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Mnganga, Tholakele (2018-10-19). "Mmabatho Montsho on going from actress to director". Channel (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-02-12.
- ↑ "Mmabatho Montsho's film wins international award". eNCA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-03-12. Retrieved 2020-02-12.
- ↑ "Mmabatho Montsho makes theatre directorial debut". www.msn.com. Retrieved 2020-02-12.
- ↑ Mathebula, Kwanele (2020-01-16). "Mmabatho Montsho's two films selected for the Pan African Film Festival". Bona Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-02-12.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Mmabatho Montsho's film wins award at US film festival". SowetanLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-02-12.
- ↑ Banks (2016-05-28). "Mmabatho Montsho Biography - Boyfriend or Husband". BuzzSouthAfrica - Famous People, Celebrity Bios, Trendy News & Updates (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-02-12.
- ↑ "MMABATHO MONTSHO WINS FILM AWARD". DailySun. Retrieved 2020-02-12.
- ↑ Davis, Desere (2020-02-12). "Halala: Mmabatho Montsho's film scoops up international award in US". Briefly (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-02-12.
- ↑ Kwach, Julie (2019-02-11). "A look into Mmabatho Montsho biography". Briefly (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-02-12.