Mobolaji Adeniyi Adeola
Arch. Mobolaji Adeniyi Adeola,FNIA (Oṣu Kẹta Ọjọ Kerindinlogun, Ọdun 1960) Oje abanikole ati Akẹẹkọ ọmọ orilẹede Naijiria o jẹ Alakoso Aree ọmọ ẹgbẹ abanikole ni orilẹ-ede Nàìjíríà o jẹ Alakoso Alakoso ti MA ati Associates ati Alakoso Obinrin Keji ti Institute of Architect ti Naijiria. [1][2][3][4]
Mobolaji Adeniyi Adeola | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kẹta 1960 |
Ẹ̀kọ́ | Ahmadu Bello University |
Iṣẹ́ | Architect,Academician |
Organization | Nigerian Institute Of Architect |
Olólùfẹ́ | Dn. (Dr.) Dapo |
Igbesi aye ibẹrẹ ati Ẹkọ
àtúnṣeA bi si idile Oloye Kolawole Olafimihan – oniwosan obstetrician ati gynecologist, ati Oloye Mrs Violet ni Ilu Lọndọnu, United Kingdom, ni Oṣu Kẹta ọjọ 16, ọdun 1960 abd ṣe igbeyawo pẹlu Dn. (Dr.) Dapo ati Alabukun fun awon omo ati omo-omo ti won n gbe ni ilu Ibadan lowolowo. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga Ahmadu Bello University Fun ìwé ẹ̀rí àkọ́kọ́ nínú iṣẹ́ abanikole, ó sì parí ẹ̀kọ́ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní 1980 ní ọdún 1982 Ó parí Degree rẹ̀ Kejì nínú iṣẹ́ abanikole ní ilé ìwé gíga Ahmadu Bello University Zaria.
Iṣẹ-ṣiṣe
àtúnṣeMobolaji jẹ Obinrin akoko ti ojẹ Aare ẹgbẹ abanikole ni orilẹ-ede Naijiria
Nigerian Institute of Architect ni Ipinle Oyo ati Aare orile-ede keji nibi ti o ti n ṣiṣẹ lọwọlọwọ gẹgẹbi 30th Aare egbe. Arabinrin naa ni Alakoso Agba ati Alabaṣepọ Agba ni MA ati Associates Mobolaji ṣiṣẹ gẹgẹ bi olukọni ni polytechnic Ibadan Oyo State Nigeria laarin ọdun 1984-1982
Omo egbe
àtúnṣeMobolaji je Aare iranse fun Institute of Architecture ti Naijiria ati Aare Obirin akoko ti egbe ni ãwẹ 63 ọdun ti o ti iṣeto. O jẹ ọmọ ẹgbẹ Igbimọ ADSL ti ile-iṣẹ ayaworan ile Naijiria.
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ https://punchng.com/it-was-tough-convincing-clients-i-could-match-male-architects-nia-president-mobolaji-adeniyi/
- ↑ https://www.nia.ng/leadership-team/
- ↑ https://guardian.ng/property/nia-pledges-mentorship-integration-of-architecture-students/
- ↑ https://www.thisdaylive.com/index.php/2023/12/27/nia-president-calls-for-urgent-measures-to-ensure-structural-integrity-in-lagos