Mobolaji Akiode
Mobolaji Iyabode Akiode (tí wọ́n bí ní May 12, 1982) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n bí sí ilẹ̀ America tó fìgbà kan jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n fún Nàìjíríà.[1] [2]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeÌlú New Jersey ni wọ́n bí i sí, ẹbí rè sì kọ lọ sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lẹ́yìn náà. Akiode padà sí United States nígbà tí ó wà ní ọmọdún mẹ́sàn-án,[3] ìlú Maplewood, New Jersey ni wọ́n sì ti tọ dàgbà. Oríṣiríṣị ìpènijà ló ní nítorí ìwọ̀ gíga rẹ̀, àmọ́ ó pegedé nínú eré-ìdárayá, ó sì mú Columbia High School wọ 1998 state championship[4] kí ó tó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ọdún 1999.[5] Akiode gba ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ láti gba bọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n ní Fordham University. Ní Fordham yìí, Akiode gba àmì-ẹ̀yẹ all-conference honors ní ọdún àgbà rẹ̀, ó sì jẹ́ agbábọ̀ọ̀lù kẹjọ ti Fordham láti ní ìkọsílẹ̀ 1,000 points àti àtúnṣe 500 lásìkò yìí. Ó sì tún gba tryout pẹ̀lú WNBA's Detroit Shock lẹ́yìn iṣẹ́ rẹ̀ ní ilé-ìwé.[6]
Ètò-ẹ̀kọ́
àtúnṣeAkiode kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ ìṣirò ní Gabelli School of business, ní Fordham University, ó sì kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ọdún 2004.[7] Ó gba oyè Masters of Business Administration láti New York University Stern School of Business ní ọdún 2014.[7]
Iṣẹ́ rẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga
àtúnṣeAkiode gba ètò ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ láti gbá bọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n ní Fordham University. Ní Fordham yìí, Akiode gba àmì-ẹ̀yẹ all-conference honors ní ọdún àgbà rẹ̀, ó sì jẹ́ agbábọ̀ọ̀lù kẹjọ ti Fordham láti ní ìkọsílẹ̀ 1,000 points àti àtúnṣe 500 lásìkò yìí. Ó sì tún gba tryout pẹ̀lú WNBA's Detroit Shock lẹ́yìn iṣẹ́ rẹ̀ ní ilé-ìwé. Wọ́n gbà á wọ inú Fordhams University basketball Hall of fame ní ọdún 2014.
Ìṣirò ti Fordham
àtúnṣeOrísun [8]
GP | Games played | GS | Games started | MPG | Minutes per game |
FG% | Field goal percentage | 3P% | 3-point field goal percentage | FT% | Free throw percentage |
RPG | Rebounds per game | APG | Assists per game | SPG | Steals per game |
BPG | Blocks per game | PPG | Points per game | Bold | Career high |
Ọdún | Ẹgbẹ́ | GP | Pọ́íǹtì | FG% | 3P% | FT% | RPG | APG | SPG | BPG | PPG |
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
1999-00 | Forham | 27 | 162 | 42.5% | 0.0% | 60.3% | 5.0 | 0.8 | 1.0 | 0.8 | 6.0 |
2000-01 | Forham | 26 | 233 | 45.5% | 0.0% | 72.4% | 5.5 | 1.1 | 0.8 | 0.6 | 9.0 |
2001-02 | Forham | 29 | 277 | 39.0% | 32.4% | 71.6% | 4.0 | 1.2 | 1.3 | 0.3 | 9.6 |
2002-03 | Forham | 30 | 495 | 40.1% | 30.6% | 77.0% | 5.4 | 1.9 | 1.4 | 0.5 | 16.5 |
Career | 112 | 1167 | 41.1% | 30.4% | 71.9% | 4.9 | 1.3 | 1.2 | 0.5 | 10.4 |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ https://www.linkedin.com/in/mobolaji-akiode-bb15a32a Àdàkọ:Self-published source
- ↑ "Mobolaji Akiode: How D'Tigress ignited my passion for Nigeria". January 12, 2019.
- ↑ "Seven Questions with Mobolaji Akiode, Sports Activist for Women".
- ↑ Huckshorn, Kristin (April 4, 2010). "Nigerian basketball star gives back". ESPN. http://sports.espn.go.com/espn/womenshistory2009/columns/story?id=5054675. Retrieved March 11, 2014.
- ↑ Delo, Cotton. "CHS '99 Grad Starts Foundation for Nigerian Girls Mobolaji Akiode, 27, recently started Hope4GirlsAfrica, a non-profit designed to increase young African women's participation in sports.", South Orange, NJ Patch, February 1, 2010. Accessed February 10, 2020. "'There's never a wrong time to do the right thing," said Akiode, 27, a 1999 graduate of Columbia High School, where she started playing basketball under Coach Johanna Wright, who bought her her first pair of basketball sneakers and with whom she still speaks constantly. Akiode came back to Maplewood for a two-week stretch, but she's currently based in Lagos, Nigeria, the country where she spent much of her childhood, though she lived in the U.S. for good starting in the early '90s."
- ↑ Fordham's Mobolaji Akiode receives tryout with the WNBA's Detroit Shock Archived 2012-07-08 at Archive.is Fordhamsports.com. 1 May 2003
- ↑ 7.0 7.1 "Mobolaji Akiode (2014) - Hall of Fame". Fordham University Athletics.
- ↑ "NCAA Statistics". web1.ncaa.org. Retrieved 2021-06-03.