Moet Abebe
Laura Monyeazo Abebe (bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógbọ̀n oṣù keje ọdún 1989) tí orúkọ inagi rẹ jẹ Moet Abebe, jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati òṣèré ni Nàìjíríà.[4] Ó béèrè sì ni di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tí ó bẹ́ẹ̀rẹ̀ sì ni ṣíṣe agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fún Soundcity TV.[5] Ó ń má ṣe atọkun fún eto One on One show, Body & Soul ati Global Countdown Show . Ní gbà ti o wa ni Soundcity, ó kópa nínú àwọn ère bíi Red card, Oasis ati Living arrangements.[6] Ní ọdún 2016, ó bẹ́ẹ̀rẹ̀ sì ni ṣe atọkun fún eto" The Takeover" ni orí Soundcity Radio 95.8Fm.[7] Ó dá ilé iṣẹ́ ti won ti ta onje kale pẹlu ìyá rẹ, orúkọ ilé iṣẹ́ náà ni LM Occasions.[8]
Moet Abebe | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Laura Monyeazo Abebe 29 Oṣù Keje 1989 United Kingdom, England |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Manchester Law[1] |
Iṣẹ́ | Video jockey [2], Radio Host, Òṣèrébìnrin[3], Catering Executive, |
Ìgbà iṣẹ́ | 2012–present |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọn bíi Laura sì orílẹ̀ èdè United Kingdom, ó sì lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Corona Ikoyi Primary School níbi tí ó tí ṣe ẹ̀kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ rẹ̀. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Dowen College fún ọdún kan, kí ó tó wà lọ sí Woldingham School àti St. Teresa's Secondary school.[9] Ní ọdún 2008, ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Manchester níbi tí ó tí kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ òfin.[10]
Iṣẹ́
àtúnṣeTV & Radio Presenter
àtúnṣeÓ sì ṣe pẹlu Soundcity TV àti Soundcity radio.[11] Ó sì ti gbà àwọn gbajúmọ̀ olórin bíi Vector (rapper), 2Baba, Olamide, Chidinma àti D'banj lóri eto rẹ.[12]
Òṣeré
àtúnṣeÓ ti kó pá ninu awọn ère bíi Red card, Oasis àti Living Arrangement.[13]
Ẹ̀bùn
àtúnṣeLaura gba ẹ̀bùn Personality of the Month láti ọwọ Meets media[14], wọn si pèé fún ẹ̀bùn agbóhùnsáfẹ́fẹ́ orí telefisionu tó tayọ julọ láti ọwọ Exquisite Magazine.[15]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Moet Abebe - Soundcity". Soundcity. July 17, 2021. Retrieved November 26, 2022.
- ↑ "Moet Abebe condemns sex-for-date theory". Vanguard News. November 25, 2022. Retrieved November 26, 2022.
- ↑ THISDAYLIVE, Home - (June 3, 2022). "Moët Abebe Signs New Deal with DSE Africa – THISDAYLIVE". THISDAYLIVE. Archived from the original on November 26, 2022. Retrieved November 26, 2022.
- ↑ JULIET EBIRIM (23 April 2015). "I believe in tasteful nudity – Moet Abebe". vanguardngr. Retrieved 14 May 2017.
- ↑ "Moet Abebe On air Television Personality". Nigerianbiography. 13 September 2015. Retrieved 14 May 2017.
- ↑ Taofik Bankole (23 March 2016). "Popular VJ, Moet Abebe shows off acting skills in new comedy series". Thenet. Retrieved 14 May 2017.
- ↑ "Soundcity Radio 98.5". Soundcity. 31 July 2016. Retrieved 14 May 2017.
- ↑ "Oap Moet Abebe Delves into Restaurant Business". Nathan Nathaniel Ekpo/Nollywoodgists.com. 25 January 2017. Retrieved 14 May 2017.
- ↑ "Moet Abebe: Soundcity VJ goes back to village to bury grandfather". Ayomide O. Tayo. 29 October 2015. Retrieved 14 May 2017.
- ↑ evatese.com Editor (16 June 2014). "All You Need To Know About Moet Abebe + Photos". evatese.com. Archived from the original on 26 April 2017. Retrieved 14 May 2017.
- ↑ "SoundCity Presenter, Moet Abebe Apologizes To Fans Over Outburst". Owolabi Oluwasegun. Retrieved 13 May 2017.
- ↑ "Vector The Viper ‘Dares’ Rappers on #TheTakeOver w/ Moet Abebe". Soundcity.tv. 5 February 2017. Retrieved 14 May 2017.
- ↑ Sola (17 March 2017). "Moet Abebe and her engagement ring drama – we investigate (PHOTOS)". Ynaija. Retrieved 14 May 2017.
- ↑ Geraldine Akutu (11 February 2017). "Meets Media celebrates Moet Abebe, Wizboy". guardian.ng. Archived from the original on 27 September 2023. Retrieved 14 May 2017.
- ↑ Ferdinand Ekechukwu (11 February 2017). "WizBoyy, Moet Abebe Emerge ‘Star Guests’". thisdaylive. Retrieved 14 May 2017.