Mohammad Yusuf Siddiq (Bẹ̀ngálì: মুহম্মদ ইউসুফ সিদ্দিক; Mohammad Yusuf Siddiq jẹ́ ọmọ Bengal, ó sì jẹ́ oníṣẹ́ ọná, òpìtàn àti ònkòwé. Àwọn iṣẹ́ rẹ̀ máa ń dálé iṣẹ́ ọnà tí ó jẹ́ mọ́ ìgbà àwọn ìjọba oni láwàní (Sultan) nínú ìtàn Bengal.

Professor
Mohammad Yusuf Siddiq
Dr
Orúkọ àbísọমুহম্মদ ইউসুফ সিদ্দিক
Ọjọ́ìbí1957 (ọmọ ọdún 66–67)
Birbhum, West Bengal
Orílẹ̀-èdèBengali
Ọmọ orílẹ̀-èdèBangali
Ẹ̀kọ́Ph.D.
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́Epigraphist, historian, professor, author, Social Worker, Philanthropist
EmployerInternational Centre for the Study of Bengal Art
OrganizationBANI (Bengal Association for Needy Peoples' Improvement)
Notable workEpigraphy of Bengal
Parents
  • Professor Dr Muhammad Mujibur Rahman (father)
  • Bilkis Begum (mother)

Siddiq Ni Ààrẹ ẹ̀gbẹ̀ tí ó ń mójú tó ọ̀rọ̀ àwọn aláìní ní Bangladẹẹṣi.

Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀ ati ẹbí rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Siddiq ní ọdún 157 sí ìdílé Mùsùlùmí Mohammad Mujibur Rahman àti Bilqis Begum,  ní Bengal. Láti abúlé Dadanchak ní ẹ̀yà Nawabganj tí ìyọ-oòrùn Pakistan tí ó ti di Bangladẹẹṣi nísìnyí. Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n àti òpìtàn. Ẹbí Siddiq kó kúrò ní abúlé Gopalganj ní ìtòsí Sujnipara, Murshidabad (ìwọ̀-oòrùn Bengal ní òni). Wọ́n jọ ìran Mandal, Khorasani sì jẹ́ Baba-nlá wọn. Ìdílé wọn ree:

Mohammad Yusuf Siddiq ọmọ Mujibur Rahman ọmọ Abdul Ghani ọmọ Ayyub Husayn ibn Haji Shahadat Mandal ọmọ Bulaqi Mandal ọmọ Nizamuddin Mandal ọmọ Abdul Karim Mandal ọmọ Haydar Ali Khan.

Ètò ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Siddiq gbọ́ èdè mẹ́wàá yanrantí. Ó kàwé gboyè ìwé gíga àkọ́kọ́ (Bachelor's degree) láti ilé ẹ̀kọ́ gíga Umm al-Qura ní Mẹkkah, Saudi Arabia.

Siddiq di ọ̀jọ̀gbọ́n-lọ́la nínú ẹ̀kọ́ Ìsìláámù ní ní ilé ẹ̀kọ́ gíga Ìsìláámù, Bangladẹẹṣi. Láàrin 1991 sí 1992, ó jẹ́ àlejò olùkọ́ni ní àgbègbè ẹ̀kọ́ gíga Ìsìláámù ní Oxford.

Siddiq ti fi ìgbà kan jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ẹ̀kọ́ gíga tí Ìtan ìsìláàmù, ọ̀làjú àtí àṣà ní ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ti ẹ̀kọ́ Ìsìláámù ní ilé ẹ̀kọ́ gíga Lahore. Ní ọdún 2011, ó di ọ̀jọ̀gbọ́n ẹ̀kọ́ Lárúbáwá ní àgbègbè ẹ̀kọ́ fún àwọn èdè àti Lítíréṣọ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ gíga Lahore, ẹ̀ka sáyẹ́nsì ìṣàkóso.

Ní ọdún 2013, wọ́n dá Siddiq lọ́lá jíjẹ́ ọmọ ẹ̀gbẹ́ ní  àgbègbè ẹ̀kọ́ gbogboògbò fún iṣé ọnà Bẹngal. Ó tí kọ oríṣiríṣi àyọkà fún ìwé àmọ̀tán-án tí Ìsìláámù (Encyclopaedia of Islam), Muqarnas, àwọn ìwé àtìgbàdégbà tí ilé ẹ̀kọ́ nípa àwọn Lárúbáwá àti àwọn aláwọ̀ dúdú (School of Oriental & African Studies), ìwé àtìgbàdégbà ti ẹgbẹ́ Ọmọ Asia ti Bangladẹẹṣi àti ìwé àtìgbàdégbà ti ilé ẹ̀kọ́ Ìsìláámù ní Oxford. Siddiq jẹ́ ọmọ ọkàn lára àwọn ìgbìmọ̀ amúṣéṣe tí ẹgbẹ́ gbogboògbò ti ìmọ̀ ẹ̀kọ́ Bẹngal láti 2018 sí 2020.[1][2]

Àwọn iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Siddiq mú iṣẹ́ ọnà Ìsìláàmù_ pàápàá jùlọ, iṣẹ́ rẹ̀ máa ń dálé iṣẹ́ ọnà tí ó jẹ́ mọ́ ìgbà àwọn ìjọba oni láwàní (Sultan) nínú ìtàn Bengal. Wọ́n gbà pè Ìwé tí ó kọ, Epigraphy and Islamic Culture,  ìwé ìtọ́ka ìtàn iṣẹ́ ọnà Ìsìláàmù tí ó ṣe pàtàkì ni Káàkiri agbègbè ọ̀hún.

Àwọn ìwé Arabic

àtúnṣe

Àwọn ìwé English

àtúnṣe
  • Mohammad Yusuf Siddiq (1989). "An Epigraphical Journey to an Eastern Islamic Land". Muqarnas. 
  • Mohammad Yusuf Siddiq (1991). Arabic and Persian texts of the Islamic inscriptions of Bengal. Watertown, Massachusetts: South Asia Press. 
  • Mohammad Yusuf Siddiq (2003). "An Ecological Journey in Muslim Bengal". Islam and ecology: A bestowed trust. Harvard University Press. pp. 451–462. 
  • Mohammad Yusuf Siddiq (2005). "Calligraphy and Islamic culture: reflections on some new epigraphical discoveries in Gaur and Pandua, two early capitals of Muslim Bengal". Bulletin of the School of Oriental & African Studies (Cambridge University Press) 68. 
  • Mohammad Yusuf SiddiqÀsìṣe ìgbéọ̀rọ̀sílẹ̀: Àìdámọ̀ ọ̀rọ̀ "etal".. "The development and use of an innovative laboratory method for measuring arsenic in drinking water from western Bangladesh". Environmental Health Perspectives. 
  • Mohammad Yusuf Siddiq (2007). "Mosque as a form of socio-cultural expression in Muslim Bengal with special reference to the Calligraphic Design of Adina Masjid". Journal of the Asiatic Society of Bangladesh (Asiatic Society of Bangladesh) 52: 197–212. 
  • Mohammad Yusuf Siddiq (2009). "The Diffusion of Islam in the Eastern Frontier of South Asia: A Fresh Approach". Jihat Al-Islam 2: 39–78. 
  • Mohammad Yusuf Siddiq (2009). "Inscription as an Important Means for Understanding the History of the Islamic East: Observations on some Newly Discovered Epigraphs of Muslim Bengal". Journal of Islamic Studies 20 (2): 213–250. doi:10.1093/jis/etn070. https://academic.oup.com/jis/article-abstract/20/2/213/715354. 
  • Mohammad Yusuf Siddiq (2009). Haque, Enamul. ed. Historical and Cultural Aspects of the Islamic Inscriptions of Bengal: A Reflective Study of Some New Epigraphic Discoveries. Dhaka: International Centre for Study of Bengal Art. 
  • Mohammad Yusuf SiddiqÀsìṣe ìgbéọ̀rọ̀sílẹ̀: Àìdámọ̀ ọ̀rọ̀ "etal". (2009). "Human serum albumin unfolding pathway upon drug binding: A thermodynamic and spectroscopic description". Journal of Chemical Thermodynamics. 
  • Mohammad Yusuf Siddiq (2011). "Spiritual Dimensions of Islam: Sufism, Sheikhs and Khanqahs of Bengal". The Varied Facets Of History: Essays In Honour Of Aniruddha Roy. Primus Books. ISBN 978-93-80607-16-0. 
  • Mohammad Yusuf Siddiq (2012). "Epigraphy and Islamic history in South Asia". Journal of Islamic Thought and Civilization 2. 
  • Mohammad Yusuf Siddiq. Advent of Islam in Bengal: An Epigraphic Approach. International Proceedings of Economics Development and Research. 
  • Mohammad Yusuf SiddiqÀsìṣe ìgbéọ̀rọ̀sílẹ̀: Àìdámọ̀ ọ̀rọ̀ "etal". (2014). "Effect of crosslinker feed content on catalaytic activity of silver nanoparticles fabricated in multiresponsive microgels". Korean Journal of Chemical Engineering (South Korea) 31. 
  • Mohammad Yusuf Siddiq (2015). Epigraphy and Islamic Culture: Inscriptions of the Early Muslim Rulers of Bengal (1205-1494). Routledge. ISBN 978-1-317-58746-0. https://books.google.com/books?id=nAUBCwAAQBAJ&pg=PA27. 
  • Mohammad Yusuf Siddiq (2016). A Descriptive Catalogue of the Arabic and Persian Inscriptions in the Bangladesh National Museum. Ministry of Cultural Affairs (Bangladesh). ISBN 978-9843390837. 
  • Mohammad Yusuf Siddiq (2017). Haque, Enamul. ed. Arabic and Persian Inscriptions of Bengal. The International Centre for Study of Bengal Art. ISBN 9789843448651. 
  • Mohammad Yusuf Siddiq (2021). Haque, Enamul. ed. "Geography, Religion and Social Life of Bengal as Reflected in Some Inscriptions". Journal of Bengal Art (The International Centre For Study of Bengal Art) 26. 

Àwọn ìwé Bengali

àtúnṣe

Àwọn ìwé Indonesia

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Executive Council". International Society of Bengal Studies. 
  2. "History". International Society of Bengal Studies. 

Ìjápọ̀ ìta

àtúnṣe