Moji Afolayan
Moji Afolayan tí wọ́n bí ní Ọjọ́ karùn-ún oṣù kejì ọdún 1969 (February 5, 1969) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí Yorùbá láti ìlú Ìbàdàn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Mojí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ bíbí olóògbé òní-sinimá àgbéléwò Adeyemi Afolayan[2] tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ade Love nígbà ayé rẹ̀. Moji Afolayan fẹ́ gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò, Razaq Olayiwola tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ojopagogo. [3]
Moji Afolayan | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ibadan, Oyo, Nigeria | 5 Oṣù Kejì 1969
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Olólùfẹ́ | Rasaq Olayiwola |
Parent(s) | Ade Love (father) |
Àwọn olùbátan | Kunle Afolayan (brother) Gabriel Afolayan (brother) Aremu Afolayan (brother) |
Iṣẹ́ Fíìmù Rẹ̀
àtúnṣeNí ọdún 2016, Afolayan tó ti ṣeré nínú ọ̀pọ̀ àwọn eré Nàìjíríà tí ó fi hàn pẹ̀lú Ojopagogo àti Dele Odule nínú eré fíìmù Yorùbá "Àrìnjó".
Ayé Rẹ̀
àtúnṣeÓ ṣe ìyàwó sí Rasaq Olasunkanmi Olayiwola, òṣèré ọkùnrin ti ilẹ̀ Nàìjíríà tí gbogbo ayé mọ̀ sí orúkọ orí ìtàgé rẹ̀, "Ojopagogo".
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Why my husband stays at home to nurse the kids-Moji Afolayan". The Nation Newspaper. Retrieved 27 February 2015.
- ↑ "Dad didn’t encourage his children to act —Kunle Afolayan". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. 2015-02-28. Archived from the original on 2015-02-28. Retrieved 2019-12-31. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Latest Nigeria news update". The Nation Newspaper (in Èdè Latini). 2018-09-03. Retrieved 2019-12-31.