Mọladé jẹ́ orúkọ ọmọ Nàìjíríà àti orúkọ oyè. O jẹ orukọ ọkùnrin pẹlu obìnrin ti orisun Yoruba, ti o tumọ si " Ọmọ jẹ ade. " [1] Orúkọ Mọladé wọ́pọ̀ láàárín àwọn ìdílé ọba ṣùgbọ́n ní báyìí, orúkọ gbogbogbòò ni.

Awọn eniyan olokiki pẹlu orukọ

àtúnṣe
  • Augustus Molade Akiwumi (1891–1985), agbẹjọro ara ilu Ghana ati oloselu
  • Molade Okoya-Thomas (1935–2015), onisowo Naijiria
  • Omolade

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.yorubaname.com/entries/molade