Molière
Jean-Baptiste Poquelin, to gbajumo bi oruko ori itage re Molière, (ìpè Faransé: [mo.ljɛːʁ]; baptised January 15, 1622 – February 17, 1673) je osere ati ako ere ara Fransi to je gbigba bi ikan ninu awon elere alawada ninla julo ninu isemookomooka.[1] Ninu awon iwe re ni Le Misanthrope (The Misanthrope), L'École des femmes (The School for Wives), Tartuffe ou L'Imposteur, (Tartuffe or the Hypocrite), L'Avare (The Miser), Le Malade imaginaire (The Imaginary Invalid), ati Le Bourgeois Gentilhomme (The Bourgeois Gentleman).
Jean-Baptiste Poquelin | |
---|---|
Portrait of Molière by Nicolas Mignard | |
Pen name | Molière |
Iṣẹ́ | Playwright |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | French |
Ìgbà | 1645-1673 |
Genre | Comedy |
Notable works | Tartuffe; The Misanthrope; The Learned Women; The School for Wives; L'Avare |
Spouse | Armande Béjart |
Partner | Madeleine Béjart |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Hartnoll, p. 554. "Author of some of the finest comedies in the history of the theater." and Roy, p. 756. "...one of the theatre's greatest comic artists."