Monalisa Chinda
òṣèré orí ìtàgé, o nṣe fíìmù àti gbajúmọ̀ orí ẹ̀rọ amóhùmáwòrán
Monalisa Chinda tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹsàn-án ọdún 1974 (13th September 1974)[1] jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò, ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ olóòtú ètò orí tẹlifíṣàn àti gbajúmọ̀ olúgbóhùnsáfẹ́fẹ́.[2]
Monalisa Chinda | |
---|---|
Monalisa Chinda ati Mr Ibu níbi àmì-ẹ̀yẹ ti Magic Viewers Choice ti ilẹ̀ Áfíríkà ni ọdún 2014. | |
Ọjọ́ìbí | Monalisa Chinda 13 Oṣù Kẹ̀sán 1974 Port Harcourt, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Ọmọ Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Òṣèrébìnrin, olóòtú sinimá àgbéléwò, olúgbóhùnsáfẹ́fẹ́ |
Ìgbà iṣẹ́ | ọdún 1996 títí di àkókò yìí |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Monalisa Chinda’s 40th Birthday Celebration". bellanaija.com. Retrieved 22 October 2014.
- ↑ "'Mona Lisa Chinda' That is not the real me". Retrieved 4 May 2014.