Àdájọba

(Àtúnjúwe láti Monarchy)

Àdájọba tabi Ìdọ́bajẹ (monarchy) je iru ijoba kan nibi ti gbogbo agbara oloselu wa patapata tabi ni oloruko lowo enikan tabi awon eyan kan. Gege bi ohun oloselu, oludajoba ni olori orile-ede, won wa nipo yi titi di igba ti wo ba ku tabi sakuro lori ite, be sini "o je yiyasoto kuro lodo gbogbo awon omo egbe orile-ede miran."[1] Eni toun solori ijoba adajoba ni aunpe ni adobaje tabi oludajoba. Iru ijoba yi lo wopo laye nigba ijoun ati oju dudu.

Lowolowo, awon orile-ede 44 ni won ni oludajoba gege bi awon olori orile-ede, 16 ninu won je Ile Ajoni ti won gba Queen Elizabeth II gege bi olori orile-ede won.

  Semi-constitutional monarchy
  Commonwealth realms (consitutional monarchies in personal union)
  Subnational monarchies (traditional)


  1. "Bouvier, John, and Francis Rawle. Bouvier's Law Dictionary and Concise Encyclopedia. 1914. 2237-2238.