Moncef Marzouki
Moncef Marzouki (Lárúbáwá: المنصف المرزوقي (al-Munṣif al-Marzūqī); ojoibi 7 July 1945) je alakitiyan eto omoniyan oniwosan ati oloselu ara Tunisia. Ni ojo 12 osu December odun 2011 o je didiboyan bi Aare ile Tunisa igbadie latowo Ile Igbimo Abagbepo. Ni Oṣu kọkanla ọdun 2021, Moncef Marzouki jẹ koko-ọrọ ti iwe-aṣẹ imuni ilu okeere fun eewu aabo ilu.
Moncef Marzouki المنصف المرزوقي | |
---|---|
President of Tunisia ad interim[1] | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 13 December 2011 | |
Alákóso Àgbà | Beji Caid el Sebsi Hamadi Jebali (Designate) |
Asíwájú | Fouad Mebazaa (Acting) |
Leader of the Congress for the Republic | |
In office 24 July 2001 – 13 December 2011 | |
Deputy | Abderraouf Ayadi |
Asíwájú | Position established |
Arọ́pò | Abderraouf Ayadi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 7 Oṣù Keje 1945 Grombalia, Tunisia |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Congress for the Republic |
Alma mater | University of Strasbourg |
Website | Official website |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedWP_president