Monica Birwinyo
Monica Jacobs Birwinyo (bíi ni ọjọ́ kẹrin oṣù kẹfà ọdún 1990) jẹ́ òṣèré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórílẹ̀ èdè Uganda. Ó ti kopa nínú àwọn eré bíi Imbabazi, The Pardon, Beauty to Ashes[1][2] , Because of U,[3] 5@home, Honorablez àti Mela and Zansanze. Ní ọdún 2012, òun àti Monica Birwinyo, Irene Aumpta àti Jacob Nsaali ṣe atọ́kun fún ètò Movie Digest Show.[4][5] Ó kópa nínú eré The Pardon gẹ́gẹ́ bí Muhoza.[6]
Monica Birwinyo | |
---|---|
Usama Mukwaya pẹ̀lú Monica Birwinyo lórí Fíímù Digest Show | |
Ọjọ́ìbí | Monica Birwinyo 4 Oṣù Kẹfà 1990 Uganda |
Iṣẹ́ | Actress, TV personality |
Ìgbà iṣẹ́ | 2010–present |
Àwọn Ìtọ́kàsi
àtúnṣe- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2021-10-19. Retrieved 2020-11-25.
- ↑ "Archived copy". Archived from the original on 2014-04-07. Retrieved 2013-04-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2021-10-19. Retrieved 2020-11-25.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2021-10-20. Retrieved 2020-11-25.
- ↑ "Archived copy". Archived from the original on 2014-04-07. Retrieved 2013-04-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Imbabazi (2013)", IMDb.