Moniepoint Microfinance Bank
Moniepoint Inc, (tí a mọ tẹ́lẹ̀ sí TeamApt Inc)[1][2] jẹ́ ilé-iṣẹ fintech tí Tosin Eniolorunda jẹ́ Oludasilẹ iléṣẹ náà ní ọdún 2015 tí o dálé lórí wí wá ọ̀nàbáyọ sí ètò ìsúnná.
Moniepointlogo.png | |
Founder(s) | Tosin Eniolorunda |
---|---|
Key people |
|
Industry |
|
Products |
Àmì-ẹ̀yẹ
àtúnṣeMoniepoint ti wà lára àwọn ilé-ìfowópamọ́ tó ti lórúkọ lórí ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lẹ́yìn tí wọ́n da sílẹ̀ ní ọdún 2022 láti ọwọ́ CB Insights.[3][4] Moniepoint tún gbàmì ẹ̀yẹ Financial Inclusion Award[5] láti ọwọ́ ilé-ìfowópamọ́ gbogboogbò ti ilẹ̀ Nàìjíríà níbi àpérò àgbááyé ti Financial Inclusion ní ọdún 2022.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Muktar, Oladunmade. "TeamApt sheds its name, rebrands as Moniepoint". TechCabal. TechCabal. Retrieved 13 January 2023.
- ↑ Oladunmade, Muktar (2023-01-21). "Moniepoint: Rebranding a Fintech Giant". TechCabal (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-17.
- ↑ Investors, King. "FINTECHOPay, Paga, Others Makes CB Insights List of Promising Fintech Startups 2022". Investors King. Investors King. Retrieved 5 October 2022.
- ↑ Oluwole, Victor (2022-10-05). "6 most promising African fintech startups as per CB Insights 2022 list". Business Insider Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-02-09.
- ↑ Olayinka, Ajayi. "CBN award institutions, individuals advancing financial inclusion in Nigeria". https://www.vanguardngr.com/2022/11/cbn-award-institutions-individuals-advancing-financial-inclusion-in-nigeria/.