Mons pubis
Ní ìmọ̀ nípa ẹ̀yà ara ènìyàn, àti ní gbogbo àwọn ẹranko tí ó lè bímọ, mons pubis (tí a tún mọ̀ sí mons, àti ní pàtó lara àwọn obìrin sí mons Venus tàbí mons veneris),[1][2] jẹ́ ibi róbótó tó lọ́rá lókè pubic symphysis ti àwọn egungun pubic.[1][2][3][4][5][6] Ní ara àwọn obìrin, ó maa ń ṣarajọ sí iwájú vulva. Ó pín sí labia majora ("ètè tó fẹ̀") ní ẹ̀gbẹ́ méjèèjì furrow tí wọ́n mọ̀ sí pudendal cleft tí ó yí labia minora, clitoris, urethra, ojú òbò àtí àwọn ẹ̀yà míràn nínú vulval vestibule.[2][5][6]
Mons pubis | |
---|---|
Details | |
Precursor | Genital tubercle |
Identifiers | |
Latin | mons pubis |
Dorlands /Elsevier | 20.htm 12541373 |
TA | A09.2.01.002 |
FMA | 20218 |
Anatomical terminology |
Ìtóbisí mons pubis kò rí bákan tí ó sì ní ṣe pẹ̀lú ìwọn kẹ́míkà ìtọ́sọ́nàn ara àti ọ̀rá ara, tí ó sì ṣeé rí dáradára lára àwọn obìrin.[1][3] Lẹ́yìn tí obìrin ba ti bàlágà, irun máa ń bo ojú ẹ̀ tí ó sì máa ń fẹ̀.[4][6][7][8] Àwọn ọ̀rá inú mons pubis maa ń gbẹgẹ́ sí estrogen, tí ó sì máa ń fa ìṣarajọ òkìtì tí obirin ba ṣẹ̀ṣẹ̀ ń bàlágà.[8] Èyì má a ń ti iwájú labia majora sí ìta kúrò nínú egungun pubic. bẹ́ gẹ́gẹ́,mons pubis má a ń sábà hàn dáradára tí estrogen ara bá ti ń dínkù tí a máa ń rí ti obìrin bá tí ń súmón ojọ́ orí tí wọn kò lè bímọ mọ́.[9]
Orúkọ mons pubis jẹyọ láti èdè Latin fún "pubic mound", àti mons Venus tàbí mons veneris jẹyọ láti èdè Latin fún "mound of Venus".[1][2]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 New Oxford American Dictionary. Oxford University Press. 2011. "The rounded mass of fatty tissue lying over the joint of the pubic bones, in women typically more prominent and also called the mons veneris."
- ↑ 2.0 2.1 2.2 2.3 Gould, A.M., M.D, George Milbry (1894). An Illustrated Dictionary of Medicine, Biology and Allied Sciences. Philadelphia: P. Blakiston, Son & Company. pp. 778–779. https://books.google.com/books?id=1cQ0AQAAMAAJ. Retrieved 2014-10-08. "Mons pubis: the eminence in front of the body and horizontal ramus of the os pubis; it is called also, in the female, mons veneris."
- ↑ 3.0 3.1 "mons pubis".
- ↑ 4.0 4.1 "mons pubis".
- ↑ 5.0 5.1 Zink, Christoph (1988). Dictionary of Obstetrics and Gynecology. Berlin: Walter de Gruyter & Co.. p. 201. ISBN 3110857278. https://books.google.com/books?id=EQlvzV9V7xIC. Retrieved 2014-10-08. "Pubic mount: mons pubis, in females mons veneris; the hairy region above the anterior commissure of the large labia or penis."
- ↑ 6.0 6.1 6.2 Basavanthappa, B.T. (2006). Textbook of Midwifery and Reproductive Health Nursing (1st ed.). New Delhi: Jaypee Brothers Medical Publishers. pp. 23, 42, 791. ISBN 8180617998. https://books.google.com/books?id=wemr8eOB9w4C. Retrieved 2014-10-08. "[Female] mons pubis (mons veneris), labia majora and minora, clitoris, prepuce of clitoris, vestibule, fourchette, and perineum… [Male] mons pubis, penis, and scrotum… Hair-covered fat pad overlying the symphysis pubis."
- ↑ Gray, Henry (1918). Lewis, Warren H.. ed. Anatomy of the Human Body. (20th ed.). Philadelphia: Lea & Febiger. ISBN 1-58734-102-6. http://www.bartleby.com/107/pages/page1265.html.
- ↑ 8.0 8.1 Myers, J.D., John E.B. (2011). The APSAC Handbook on Child Maltreatment (3rd ed.). Thousand Oaks, California: SAGE Publications. ISBN 1412966817. https://books.google.com/books?id=zP3ql9puzvQC. Retrieved 2014-10-08.
- ↑ Braun, Kirsten (2007-09-01).
Àwọn ìwé ìtàn
àtúnṣe- Sloane, Ethel. Biology of Women. Cengage Learning 2002, ISBN 978-0-7668-1142-3, p. 31
- Gray, Henry: Anatomy of the Human Body. Lea & Febiger, 1918
- "Mons pubis" in Encyclopædia Britannica Online. 2010.
Àwọn àjápọ̀ látìta
àtúnṣe- Media related to Mons pubis at Wikimedia Commons
- Anatomy photo:41:02-0102 at the SUNY Downstate Medical Center – "The Female Perineum: The Vulva"