Moses Bliss
Moses Bliss Uyoh Enang,ti ọpọlọpọ awọn ẹniyan mọ si Moses Bliss (wọn bi ni ogunjo osu keji,odun 1995)o je akọrin ọmọ oriledẹ Niajiria,ada esin ati oluko orin.o je oludasile "Spotlite Nation", ile ise orin orilede Naijiria.