Moyo Lawal
Moyọ̀ Lawal jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà[1][2][3][4][5]. Ó gbà àmì ẹ̀yẹ Revelation of the Year láti ọ̀dọ̀ Nollywood Awards ní ọdún 2012.[6]
Moyo Lawal | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | January 1 Badagry, Lagos State |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Lagos |
Iṣẹ́ | Actress |
Notable work | Holding Hope |
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Lawal sí ìlú Badagry. Ó gboyè nínú ìmò Creative arts láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Yunifásítì ìlú Èkó.[7][8]
Iṣẹ́
àtúnṣeÓ kópa nínú ìdíje Next Movie Star àmọ́ kò yege níbẹ̀.[9] Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe nínú eré Shallow Waters, ó sì kó ipa Chioma nínú eré náà. Lawal di gbajúmọ̀ nígbà tí ó kó ipa Chinny nínú eré Tinsel. [10] Ní ọdún 2012, ó gbà àmì ẹ̀yẹ Revelation of the Year láti ọ̀dọ̀ BON Awards.[11]
Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe
àtúnṣe- Holding Hope[12]
- A Time To Heal
- A Toast To Heartbreak
- Emem and Angie
- Madam’s PA
- Tangled Web
- Millenium Parent
- Desperate Baby Mama
Àwọn Ìtọ́kàsi
àtúnṣe- ↑ Oladotun, Olayemi (2019-11-03). "Moyo Lawal Reveals Secrets Behind Her Controversial Character On Social Media". Information Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-24.
- ↑ Odusanya, Rachael (2018-06-18). "Top interesting facts from biography of a popular actress Moyo Lawal". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-26.
- ↑ Published. "Moyo Lawal speaks for robbery victims". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-25.
- ↑ "Actress, Moyo Lawal Survives Robbery Attack on Third Mainland Bridge". Nigerian Voice. Retrieved 2019-11-25.
- ↑ "Actress narrates sick ordeal, armed robbery attack". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-02-03. Archived from the original on 2020-02-04. Retrieved 2019-11-25.
- ↑ Aiki, Damilare (2012-11-13). "Joseph Benjamin, Nse Ikpe-Etim, Moyo Lawal & Alex Ekubo Win Top Awards at the 2012 Best of Nollywood Awards (BON) in Lagos – First Photos & Full List of Winners". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-24.
- ↑ "10 Things You Didn't Know About Moyo Lawal". Youth Village Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-04-15. Archived from the original on 2019-06-14. Retrieved 2019-11-24.
- ↑ Published. "People touch my body to know if it’s real —Moyo Lawal". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-26.
- ↑ Adeniran, Raphel (2019-03-23). "Nollywood Celebrities Who Rose To Fame From Reality Shows". Eelive (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-24.
- ↑ "10 Things You Didn't Know About Moyo Lawal". Youth Village Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-04-15. Archived from the original on 2019-06-14. Retrieved 2019-11-24.
- ↑ Aiki, Damilare (2012-11-13). "Joseph Benjamin, Nse Ikpe-Etim, Moyo Lawal & Alex Ekubo Win Top Awards at the 2012 Best of Nollywood Awards (BON) in Lagos – First Photos & Full List of Winners". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-24.
- ↑ "Holding Hope Full Cast & Crew - nlist nlist | Nollywood, Nigerian Movies & Casting". nlist.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-27.