Mr 2kay
Abinye David Jumbo tí wọ́n bí ní (February 11, ọdún 1988), tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Mr 2Kay, jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó fìgbà kan tẹwọ́bọ̀wé iṣẹ́ pẹ̀lú Grafton Entertainment, àmọ́ ó kúrò ní ọdún 2018, láti lọ ṣe ìdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ orin rẹ̀, tó pè ní Better Life Entertainment.[1][2]
Mr 2Kay | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Abinye David Jumbo |
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Kejì 1988 Port Harcourt, Rivers State Nigeria |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Rivers State, Nigeria |
Irú orin | Afro pop music |
Occupation(s) | Singer, songwriter, performer |
Years active | 2010–present |
Labels | Better Life Entertainment |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Fighting Their Way to Stardom". AllAfrica. 5 January 2014. http://allafrica.com/stories/201401061760.html. Retrieved 12 August 2015.
- ↑ "FACTORY78 – Mr 2Kay Performs Bubugaga Live / Face-off interview". Naija Celebrity. Archived from the original on 10 September 2018. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)