Mufti Abdul Razzaq
Mufti Abdul Razzaq (tí orúkọ àdàpè rẹ a máa jẹ́ (ABDUL Razzaque Khan; lati 13 August 1925 títí dé 26 May 2021) jẹ́ onímọ̀ ẹ̀kọ́ èsìn Islamu ati ọmọ india, Mufti tí ó tun jẹ́ ajìjàgbara fun òmìnira ilẹ̀ india, ti o sin orílẹ̀ ede rẹ̀ ní ipò kẹsan akọ̀we àgbà fun Jamiat Ulama-e-Hind. òun nígbà ayé rẹ̀ ni igbákejì ààrẹ fun ipin Jamiat Ulama-e-Hind's Arshad. ó se ìdásílẹ̀ Madrasa Jamia Islamia Arabia ni Bhopal.
Ọ̀rọ̀ Àkọsílẹ̀
Abdul Razzaq ti wọn bí ní 13 August 1925. tí ó sì kọ́ ẹ̀kọ́ ni Masjid Malang Shah, Jamia Darul Uloom Ilāhiya àti Jamia Aḥmadiya in Bhopal. Ní July 1952, ó darapọ̀ mọ́ Darul Uloom Deoband lati parí ẹ̀kọ́ rẹ. ó kẹkọ nípa Sahih Bukhari pẹlu Hussain Ahmad Madani; Sahih Muslim pẹlu Fakhrul Hasan Moradabadi; ami' al-Tirmidhi pẹlu Muḥammad Ibrāhim Balyawi; Sunan Abu Dawud pẹlu Bashīr Aḥmad; Sunan Nasai ati Sunan ibn Majah pelu Mubārak Hussain; Muwatta Imām Muḥammad pẹlu Meraj-ul-Haq Deobandi; Muwatta Imam Malik pelu Sayyid Hasan; Shama'il Muhammadiyah pẹluMuhammad Tayyib Qasmi; and Sharah Wiqāyah pẹlu Muhammad Salim Qasmi. Ó parí ẹ̀kọ́ lori "dars-e-nizami" ni 1377 AH o si mu "ifta" lo kunkundun pẹlu Mahdi Hasan Shahjahanpuri.
Razzaq kópa ninu ìjìjàgbara fún òmìnira india. ni odun 1947, ó kópa nínú ìjà tí ówáyé ni aarin ẹgbẹgun Bhopal's Qazi ati awon afipakónilẹ́rú Britiko ni ọdun 1958, ó ṣe ìdásílẹ̀ Madrasa Jamia Islamia Arabia, ọ̀kan lara ilé ẹ̀kọ́ islam tí ó pẹ́ julọ ni Bhopal. Ó jẹ́ baba ẹgbẹ́ fun orisirisi ile- ẹ̀kọ́ islam ni Madhya Pradesh. oun sì tún ni ààrẹ-ìpínlẹ̀ fun Darul Uloom Deoband's "Rābta Madāris-e-Islamiya" fún Madhya Pradesh. Ó gba oríyìn fn ìdàgbà àti ìlọsíwáju Jamiat Ulama-e-Hind ni Madhya Pradesh. oun ni akkọ̀wé àgbà fun Jamiat Ulama-e-Hind láti 1991 si 1994 Ó sisẹ́ gẹ́gẹ́bi igbákejì aarẹ (fun orilẹ ede) àti ààrẹ-ìpínlẹ̀ fun Madhya Pradesh (ìpin Arshad), Ni ọdun 1958, wọn yan ni igbakeji mufti ti Bhopal's "Darul Qadha" (ile ẹjọ́ islamu); ati adajọ́ àgbà ni odun 1968. O jẹ́ Mufti ti ilu Bhopal fun 1974 titide 1983. Arii gẹ́gẹ́bí- olori awọn mufti (Mufti-e-Azam) ni Madhya Pradesh. Ó gbé ibasepọ lárugẹ laarin awòn ẹlẹsinjẹsin nípa gbigbe ìpadé kalẹ̀ larin awọn olorí ẹlẹsin gbogbo. Ọ̀rọ̀ ati àṣẹ rẹ̀ múlẹ̀ larin àwọn mùsùlùmí láti pẹ̀tu sí ìjà agbègbè lọ́na ti o yẹ.
Ni ọdun 2016, ó kẹgan ìhùwàsí Rashtriya Swayamsevak Sangh, Vishva Hindu Parishad ati Bajrang Dal ni Madhya Pradesh; o sọ fún àwọn musulumi láti di allafia mú dípò íjà tàbí àwọn ohun tole da omi alafia ìlú rú. o sọọ kalẹ wípé bí ẹnikẹni bá dojú kọwọ́n tí kò bá sí ohun tí wọn leeṣe kí wọn pa onítọ̀hún tàbi kí wọn yonda ẹ̀mí ti wọn láti dóòla ẹnikeji wọn. O si tún wí fún àwọn adarí olósèlu Madhya Pradesh kí wọn ṣẹ àwon ti apákejì lọ́wọ́ kí wọn ye gbógun sí àwọn musulumi. O tún sọọ kalẹ̀ wípé, tí wọn ko ba dáwọ́dúró, kòsí mámugàrí lọwọ́ àwon musulumi o. Anandiben Patel ti se gomina Madhya Pradesh, bu ọla fun Razzaq ní January 2021 fun ipa tí ó kó nínu ìjàgbara ti orílẹ̀-ède India.
Razzaq kú ní 26 May 2021. Digvijaya Singh, Kamal Nath atiShivraj Singh Chouhan kẹ́dùn ikú rè. wọn ṣe ayẹyẹ ìbùọlafunni fun un ki wọn to sin ara òkú rẹ̀.
Awon Iwe Atejade
àtúnṣeAbdul Razzāq authored more than 50 books including:
- Sarzamīn-e-Hind: Ambiyā Kirām aur Islām
- Qur'ān Main Kya Hai?
- Āzādi, Aslāf aur Jamiat Ulama-e-Hind
- Islāmi Zindagi: Paidā'ish Se Jannat Tak
- Ahle Qur'ān aur Ahle Kitāb
Àwọn itọ́kasí
àtúnṣe"مجاہد آزادی مفتی عبد الرزاق خان دار فانی سے کوچ کر گئے" [Freedom struggle activist Mufti Abdul Razzaq passes away]. ETV Bharat. 27 May 2021. Archived from the original on 4 June 2021. Retrieved 4 June 2021.
Abdul Mabood Qasmi, Mufti Abdur Razzāq Khān, Halāt-o-Khidmāt m'a Tārīkh Tarjuma wāli Masjid (June 2010 ed.), p. 113
Abdul Mabood Qasmi, Mufti Abdur Razzāq Khān, Halāt-o-Khidmāt m'a Tārīkh Tarjuma wāli Masjid (June 2010 ed.), p. 139
Abdul Mabood Qasmi, Mufti Abdur Razzāq Khān, Halāt-o-Khidmāt m'a Tārīkh Tarjuma wāli Masjid (June 2010 ed.), pp. 146–149
Abdul Mabood Qasmi, Mufti Abdur Razzāq Khān, Halāt-o-Khidmāt m'a Tārīkh Tarjuma wāli Masjid (June 2010 ed.), pp. 241–242
"مفتی عبدالرزاق خان بھوپالی نائب صدر جمعیۃعلماءہند وفات پاگئے" [Mufti Abdul Razzaq Khan Bhopali, vice-president Jamiat Ulama-e-Hind, passes away]. Baseerat Online. 27 May 2021. Retrieved 26 May 2021.
"नहीं रहें मुफ्ती अब्दुल रज्जाक साहब:मुफ्ती ए आज़म अब्दुल रज्जाक साहब का इंतकाल, शहरभर में शोक की लहर". Dainik Bhaskar (in Hindi). Retrieved 26 May 2021.
Abdul Mabood Qasmi, Mufti Abdur Razzāq Khān, Halāt-o-Khidmāt m'a Tārīkh Tarjuma wāli Masjid (June 2010 ed.), pp. 340–341
Salman Mansoorpuri, ed. (May 2012). Tazkirah Fidā-e-Millat. New Delhi: Jamiat Ulama-e-Hind. pp. 1042–1044. Retrieved 12 July 2021.
Abdul Mabood Qasmi, Mufti Abdur Razzāq Khān, Halāt-o-Khidmāt m'a Tārīkh Tarjuma wāli Masjid (June 2010 ed.), p. 329
Abdul Mabood Qasmi, Mufti Abdur Razzāq Khān, Halāt-o-Khidmāt m'a Tārīkh Tarjuma wāli Masjid (June 2010 ed.), p. 222
"مفتی اعظم مدھیہ پردیش مجاہد آزادی مفتی عبدالرزاق کی رحلت" [The demise of Mufti Abdul Razzaq, the Grand Mufti of Madhya Pradesh]. Asre Hazir (in Urdu). Retrieved 6 June 2021.
"Bhopal: Prominent Muslim cleric Mufti Abdul Razzaq passes away in Bhopal, heavy police force deployed in old city to enforce Covid Protocol". The Free Press Journal. 27 May 2021. Retrieved 27 May 2021.
Sameer (19 January 2016). "Mufti Abdul Razzaq instructs Muslims what to do during riots". The Siasat Daily.
Abdul Mabood Qasmi, Mufti Abdur Razzāq Khān, Halāt-o-Khidmāt m'a Tārīkh Tarjuma wāli Masjid (June 2010 ed.), pp. 258–260
"Governor honors 12 freedom fighters". mpinfo.org. 27 January 2021. Retrieved 26 May 2021.
"MP: Freedom fighter and Islamic scholar dies". Outlook, India. 27 May 2021. Retrieved 27 May 2021.
"मुफ्ती अब्दुल रज्जाक को गार्ड ऑफ ऑनर देकर किया गया सुपुर्द ए खाक". Nai Dunia (in Hindi). 27 May 2021. Retrieved 28 May 2021.
Abdul Mabood Qasmi, Mufti Abdur Razzāq Khān, Halāt-o-Khidmāt m'a Tārīkh Tarjuma wāli Masjid (June 2010 ed.), pp. 326–327