Muhammad Ali Pasha (Lárúbáwá: محمد علي باشا‎; tí a bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹta ọdún 1769 tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ kejì oṣù kẹjọ ọdún 1849)[lower-alpha 1] jẹ́ gomina Ottoman[2] àti adarí orílẹ̀ èdè Ìjíptì láàrin ọdún 1805 sí 1848, ọ̀pọ̀ káà mọ́ ara àwọn tí ó kọ́ Íjíptì òde òní. Nígbà tí ìjọba rẹ̀ tàn, ó dárí Egypt, Sudan, Hejaz, Najd, Levant, Cyprus àti apá kan Greece.

Muhammad Ali
Pasha

Àwòrán Muhammed tí Auguste Couder yà ní ọdún 1840
Reign 17 May 1805 – 2 March 1848
Predecessor Hurshid Pasha
Successor Ibrahim Pasha
Spouse
  • Amina Hanim
  • Mahduran Hanim
  • Ayn al-Hayat Qadin
  • Mumtaz Qadin
  • Mahwish Qadin
  • Namshaz Qadin
  • Zayba Khadija Qadin
  • Shams Safa Qadin
  • Shami Nur Qadin
  • Umm Numan
  • Naila Qadin
  • Gulfidan Qadin
  • Qamar Qadin
Issue
Father Ibrahim Agha
Mother Zeinab
Born 4 March 1769
Kavala, Sanjak of Kavala, Rumelia Eyalet, Ottoman Empire
Died 2 August 1849(1849-08-02) (ọmọ ọdún 80)
Ras el-Tin Palace, Alexandria, Egypt Eyalet, Ottoman Empire
Burial Mosque of Muhammad Ali, Cairo Citadel, Egypt
Religion Sunni Islam

Ó jẹ́ olórí ogun nínú àwọn ọmọ ológun Albania tí wọ́n rán láti gba Íjìptì lọ́wọ́ ìjọba France lábẹ́ Napoleon. Lẹ́yìn ìgbà tí Napoleon fi ilé náà sílẹ̀, Muhammad Ali di gómìnà Wāli (gọ́minà) Ìgìptì, ó sì di Pasha.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Khalid Fahmy (1998). All the Pasha's Men: Mehmed Ali, his Army and the Making of Modern Egypt. Cambridge University Press. 
  2. Özavcı, Hilmi Ozan (2021). Dangerous Gifts: Imperialism, Security, and Civil Wars in the Levant, 1798-1864. Oxford University Press. ISBN 978-0-19-885296-4. https://books.google.com/books?id=Lbo0EAAAQBAJ. 


Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/> tag was found