Muhammad Haji Ibrahim Egal

Mohamed Haji Ibrahim Egal (Lárúbáwá: محمد حاجي إبراهيم عقال‎; August 15, 1928 – May 3, 2002) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Somalia nígbà ayé rẹ̀. Òun ni ó jẹ́ ààrẹ orílẹ̀ èdè Somaliland láàrin ọdún 1993 títí di ìgbà tí ó fi ayé sílẹ̀ ní ọdún 2002. Ó di ipò mínísítà orílẹ̀ ède rẹ̀ mú fún ọjọ́ mọ́kànlá láti oṣù kẹfà sí oṣù keje ọdun 1960, ó sì tún lọ sáà mìíràn nípò kan náà láàrin ọdún 1967 sí 1969.[3]

Mohamed Haji Ibrahim Egal
محمد حاجي إبراهيم عقال
Egal in 1968
2nd President of Somaliland
In office
May 16, 1993 – May 3, 2002
Vice PresidentAbdirahman Ahmed Ali Tuur (1993–1995)[1]
Abdirahman Aw Ali Farrah (1995–1997)[2]
Dahir Riyale Kahin (1997–2002)
AsíwájúAbdirahman Ahmed Ali Tuur
Arọ́pòDahir Riyale Kahin
1st & 4th Prime Minister of the Somali Republic
In office
July 1, 1960 – July 12, 1960
ÀàrẹAden Adde
AsíwájúAbdullahi Issa (as the prime minister of the Trust Territory of Somalia)
Arọ́pòAbdirashid Ali Shermarke
In office
July 15, 1967 – October 21, 1969
ÀàrẹAbdirashid Shermarke
AsíwájúAbdirizak Haji Hussein
Arọ́pòMuhammad Ali Samatar
Prime Minister of the State of Somaliland
In office
June 26, 1960 – July 1, 1960
AsíwájúOffice established
Arọ́pòOffice abolished
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1928-08-15)Oṣù Kẹjọ 15, 1928
Odweyne, British Somaliland (now Somaliland)
AláìsíMay 3, 2002(2002-05-03) (ọmọ ọdún 73)
Pretoria, South Africa
Ẹgbẹ́ olóṣèlúUnited Peoples' Democratic Party
Somali Youth League
(Àwọn) olólùfẹ́(1) Edna Adan
(2) Asha Saeed Aabi
(3) Hawa Ainab
(4) Kaltum Haji Dahir
Alma materSOS Sheikh Secondary School
Signature

Ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

A bí Egal ní ọdún 1928, ní Odweyne. Ó wá láti ilé Issa Musse ti ìdílé Habar Awal ní ẹ̀ya Isaaq.

Ó ka ìwé prámárí àti sẹ́kọ́ndírí rẹ̀ ní British Somaliland kí ó tó lọ sí United Kingdom. Egal fẹ́ Asha Saeed Abby ní ìyàwó, àwọn méjèèjì sì fẹ́ ọmọkùnrin mẹ́ta àti ọmọbìnrin méjì.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Paquin, Jonathan (July 1, 2010). A Stability-Seeking Power: U.S. Foreign Policy and Secessionist Conflicts. McGill-Queen's Press - MQUP. ISBN 9780773591028. https://books.google.com/books?id=wWv4dHWjDpUC. 
  2. Bahcheli, Tozun; Bartmann, Barry; Srebrnik, Henry (September 9, 2004). De Facto States: The Quest for Sovereignty. Routledge. ISBN 9781135771218. https://books.google.com/books?id=Gk2QAgAAQBAJ. 
  3. "Somaliland's Quest for International Recognition and the HBM-SSC Factor". Archived from the original on May 28, 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)