Mukakamanzi Beatha
Mukakamanzi Beatha jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdèRùwándà.[1] Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Giramata gẹ́gẹ́ bi ìyá sí Giramata.[2]
Mukakamanzi Beatha | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Mukakamanzi Beatha Kigali, Rwanda |
Orílẹ̀-èdè | Rwandan |
Iṣẹ́ | Actress |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Find out more about famous movies like Mama Nick". imvahonshya. Archived from the original on 14 November 2021. Retrieved 14 October 2020.
- ↑ "Judge Beatha gave advice to filmmakers in a negative light". inyarwanda. Retrieved 14 October 2020.