Mukarama Abdulai
Mukarama Abdulai jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 16, óṣu October ni ọdun 2002. Arabinrin naa ṣere fun Deportivo Alavés Gloriosas gẹgẹbi striker[1][2][3]
Àṣeyọri
àtúnṣe- Mukarama gba ami ẹyẹ gẹgẹbi agbabọọlu lobinrin ti ọdun 2019[4].
Itọkasi
àtúnṣe- ↑ https://ghanasoccernet.com/black-princesses-striker-abdulai-mukarama-joins-spanish-club-deportivo-alaves-femenino
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-06-23. Retrieved 2022-06-23.
- ↑ https://www.eurosport.com/football/mukarama-abdulai_prs521064/person.shtml
- ↑ https://ng.soccerway.com/players/abdulai-mukarama/517445/