Mukhtar Shehu Idris
Olóṣèlú
Mukhtar Shehu Idris (a bi ní ọjọ kẹrin, oṣù kẹrin ọdún 1974) jẹ alabojuto ati olóṣèlú Naijiria. Òún ni Gomina ti a yan ni ìpínlẹ̀ Zamfara nínú idibo gómìnà ọdún 2019 lábẹ́ ẹgbẹ́ All Progressive Congress (APC).[1][2]
Àwọn itọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "JUST IN: APC's Mukhtar wins Zamfara governorship election". Daily Trust. March 11, 2019. Retrieved 15 March 2019.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "APC wins Zamfara Governorship election with 534,541 votes". guardian.ng. March 11, 2019. Archived from the original on 14 June 2021. Retrieved 15 March 2019.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |