Munezero Aline

Munezero Aline (tí wọ́n bí ní ọdún 1994) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Rùwándà.[1] Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bi "Milika" nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Gica.[2]

Munezero Aline
Ọjọ́ìbíMunezero Aline
1994
Kigali, Rwanda
Orílẹ̀-èdèRwandan
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́2015–present

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. "Who is Aline Munezero, one of the most popular filmmakers in Rwanda?". inyarwanda. Retrieved 14 October 2020. 
  2. "Milka lost her choice between Junior and Rocky". isimbi. Retrieved 14 October 2020.