Murphy Afolabi

(Àtúnjúwe láti Murphy Afọlábí)

Murphy Afolabi tí wọ́n bí ní Ọjọ́ karùn-ún oṣù karùn-ún ọdún 1974 (5th May, 1974) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré, olùdarí àti oǹkọ̀tàn sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. [1] [2]

Murphy Afọlábí dii olóògbé níí Ọjó kẹ́rínlà oṣù karùn-ún ọdún 2023 (14th May, 2023).

Ìgbà èwe, aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ àti iṣẹ́ tíátà rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Afọlábí ni ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ ìbánisọ̀rọ̀, tíátà àti ètò nípa ṣíṣe sinimá ni ile ìwé Ìré Polytechnic. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà lábẹ́ àgbà òṣèré sinimá àgbéléwò tí a mọ̀ sí Dágúnró, nígbà tí ó kópa nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Ifá Olókun. Lẹ́yìn èyí ó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò tí ó ti ju ọgọ́ta lọ. [3]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Tersoo, Andrella (2018-07-25). "Murphy Afolabi's biography, career, children and other interesting facts". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2020-01-07. 
  2. Eromosele, Oamen (2019-07-05). "Murphy Afolabi holds audition for upcoming artistes". The Nation Newspaper. Retrieved 2020-01-07. 
  3. "Murphy Afolabi Biography: Age & Net Worth". 360dopes. 2018-07-16. Retrieved 2020-01-07.