Ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbagbà
(Àtúnjúwe láti Musa paradisiaca)
Ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbagbà (Musa × paradisiaca), jẹ́ èso kan lára èso igi oko nínú ìran Musa tó ṣe é sè jẹ, bójẹ lásán, dín, yan tàb lò fún Ó jẹ bí òkèlè. Ó yàtọ̀ sí àwọn ọ̀gẹ̀dẹ̀ wẹẹrẹ tó ṣe é fi ṣe ìpanu.
Ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbagbà àti àwọn irú ọ̀gẹ̀dẹ̀ míràn | |
---|---|
Osi de otun: Ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbagbà, ogede pupa, ogede wewe, Cavendish bananas. | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Ìjọba: | |
(unranked): | |
(unranked): | |
(unranked): | |
Ìtò: | |
Ìdílé: | |
Ìbátan: | |
Irú: | M. paradisiaca
|
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Musa × paradisiaca |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |