Musanase Laura (tí wọ́n bí ní ọdún 1993) jẹ́ òṣèrébìnrin lórílẹ̀-èdè Rùwándà.[1] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òṣèrébìnrin tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní orílẹ̀-èdè Rùwándà látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó nínu eré tẹlifíṣọ̀nù aláwàdà kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ City Maid.[2]

Musanase Laura
Ọjọ́ìbíMusanase Laura
1993
Tanzania
Orílẹ̀-èdèRwandan
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́2018–present

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Much more you didn't know about NIKUZE "CityMaid" you are vying for the award for Best Actor". inyarwanda. Retrieved 14 October 2020. 
  2. "Meet actress Laura Musanase". newtimes. Retrieved 14 October 2020. 

Àwọn ìtakùn Ìjásóde

àtúnṣe