Museu Nacional de História Natural de Angola

Museu Nacional de História Natural de Angola (èdè Yoruba: musíọ́mù àgbà ti Angola fún ìtàn) jẹ́ musíọ́mù kan ní agbègbè Ingombota ní ìlú Luanda, Angola. Òun nìkan ni musíọ́mù ìtàn ni orílẹ̀ èdè Angola.

Wọ́n dá musíọ́mù náà kalẹ̀ ní ọdun 1938 gẹ́gẹ́ bi Museu de Angola,[1] ó sì kọ́kọ́ wà ní Fortress of São Miguel, ó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ka nípa ẹranko, àwòrán àti ìtàn. Odún 1956, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí ń lọ ilé alájà mẹta ní Ingombota.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Directory of museums in Africa. Kegan Paul International. 1 January 1990. p. 28. ISBN 978-0-7103-0378-3. https://books.google.com/books?id=06ohAQAAIAAJ.