Musiliu Obanikoro
Olóṣèlú Naijiria
Musiliu Obanikoro je agba oloselu omo bibi ilu Eko nile Yoruba lapa gusu iwo-oorun orile-ede Naijiria.[1] O ti figba kan je asofin-agba (Senator) ni odun 2003 si 2007 nibiti o ti soju ipinle Eko nile igbimo asofin-agba. Ni odun 2014, Aare-ana, Goodluck Jonathan yan-an gegebi Minister-kereje fun aabo orile-ede (Defense Minister Of state).[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Awon Itokasi
àtúnṣe- ↑ "About Obanikoro". Senator Obanikoro (in Èdè Ruwanda). Archived from the original on 2019-09-21. Retrieved 2019-09-21.
- ↑ "Musiliu Obanikoro". Wikipedia. 2007-02-01. Retrieved 2019-09-21.