Mustafa El Haddaoui
Mustafa El Haddaoui (Ni ede larubawa: مصطفى الحداوي) ni a bini ọjọ keji dinlọgbọn, óṣu july ni ọdun 1961 ni ilu Casablanca jẹ akọṣẹmọṣẹ agbabọọlu afẹsẹgba to ti fi ẹyinti[1].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Mustapha El-Hadaoui | ||
Ọjọ́ ìbí | 28 Oṣù Keje 1961 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Casablanca, Morocco | ||
Ìga | 1.81 m (5 ft 11 in) | ||
Playing position | Midfielder | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
1979–1985 | Raja Casablanca | ||
1985–1987 | Lausanne Sports | 23 | (7) |
1987–1988 | AS Saint-Étienne | 33 | (10) |
1988–1990 | OGC Nice | 58 | (4) |
1990–1993 | RC Lens | 84 | (14) |
1993–1995 | Angers SCO | 65 | (9) |
1996–1997 | SS Jeanne d'Arc | ||
National team | |||
1982–1994 | Morocco national football team | 47 | (10) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣèyọri
àtúnṣeMustapha lo ọpọlọpọ igba rẹ gẹgẹbi àkọṣẹmọṣẹ agbabọọlu afẹsẹgba ni ilu france. Arakunrin naa wa lara awọn elere to kopa ninu Cup FIFA agbaye to waye ti ọdun 1986 ati 1994[2]. Mustapha dije ninu Olympic ti Summer nibi to ti ṣoju fun órilẹ ede Morocco ni ọdun 1984[3][4]