Mustapha El Biyaz
Mustapha El-Biyaz ni a bini ọjọ kejila, óṣu February ni ọdun 1960 ni Taza jẹ elere bọọlu afẹsẹgba defender ti órilẹ ede Morocco to ti fi ẹhinti. El Biyaz ṣèrè fun Club KAC Marrakech ninu Botola[1][2][3][4][5].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Mustapha El-Biaz | ||
Ọjọ́ ìbí | 12 Oṣù Kejì 1960 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Taza, Morocco | ||
Ìga | 1.73 m (5 ft 8 in) | ||
Playing position | Defender (association football) | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
– | KAC Marrakech | ||
1987–1988 | F.C. Penafiel | 1 | (0) |
National team | |||
1980–1988 | Morocco national football team | 42 | (2) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣèyọri
àtúnṣeBiyaz kopa ninu Olympic Summer ti ọdun 1984 ati Cup FIFA Àgbayè ti ọdun 1986[6]. Ni ọdun 2006, CAF yan Mustapha gẹgẹbi ọkan lara awọn igba elere bọọlu afẹsẹgba to dara ju ni ilẹ afirica lati adọta ọdun sẹyin[7].