Mustapha Fadli
Mustapha Fadli jẹ afẹṣẹja ti órilẹ ede Morocco. Fadli kopa ninu idije awọn ọkunrin omi ara to fuyẹ(men's lightweight) ni Summer Olympic to waye ni ọdun 1984[1][2][3][4]
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Ọmọorílẹ̀-èdè | Moroccan |
Sport | |
Erẹ́ìdárayá | Boxing |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Mustapha Fadli Profile
- ↑ Men's Lightweight
- ↑ First Olympic Games
- ↑ "Mustapha Fadli’s career". Archived from the original on 2023-03-17. Retrieved 2023-03-17.