Mykola Azarov
Mykola Azarov (Ukrania: Микола Янович Азаров, Mykola Yanovych Azarov; ibi gege bi Nikolay Yanovich Pakhlo (Rọ́síà: Николай Янович Пахло) December 17, 1947, Kaluga, Russia) ni Alakoso Agba orile-ede Ukraine lati March 11, 2010.
Mykola Yanovych Azarov Микола Янович Азаров | |
---|---|
Prime Minister of Ukraine | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga March 11, 2010 | |
Ààrẹ | Viktor Yanukovych |
Deputy | Andrii Kliuyev |
Asíwájú | Oleksandr Turchynov (Acting) |
In office January 5, 2005 – January 24, 2005 | |
Ààrẹ | Viktor Yushchenko |
Asíwájú | Viktor Yanukovych |
Arọ́pò | Yulia Tymoshenko |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kejìlá 1947 Kaluga, Russian SFSR, Soviet Union |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Party of Regions |
Website | Official website |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |