Myralyn Osei Agyemang
Myralyn “Mimi” Nartey jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ karun, óṣu November ni ọdun 1981. Agbabọọlu naa ṣere fun Portland Rain gẹgẹbi forward.
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Myralyn Nartey | ||
Ọjọ́ ìbí | 5 Oṣù Kọkànlá 1981 | ||
Ibi ọjọ́ibí | United States | ||
Playing position | Forward | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2001–2003 | Portland Rain | ||
National team‡ | |||
1998–2003 | Ghana women's national football team | 3 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Myralyn kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ti ọdun 2003.