Nàkádà Kẹta
Nàkádà Kẹta ni igba to pari igba Nawada to siwaju igba Egypti ayeijoun, igba na bere lati 3200 de 3000 SK.[1] Igba yi gan ni igbese to da orileijoba sile, to ti bere lati igba Nakada keji, bere daada, pelu awon oba olori. Nakada Keta tun unje titokasi bi Iran-oba 0 tabi Igba Iran-oba akobere[2] lati fihan pe oba olori wa nibe otilejepe oba yi le mo je lati iran-oba kankan.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Shaw, Ian, ed (2000). The Oxford History of Ancient Egypt. Oxford University Press. p. 479. ISBN 0-19-815034-2.
- ↑ Shaw, Ian, ed (2000). The Oxford History of Ancient Egypt. Oxford University Press. p. 479. ISBN 0-19-815034-2.