Núkléù átọ̀mù
Núkléù ni ibi kiki to ni protoni ati neutroni ni arin atomu. O je wiwari ni 1911, nipase itumo ti Ernest Rutherford fun idanwo Rutherford 1909 ti Hans Geiger ati Ernest Marsden se, labe idari Rutherford. Afiwera protoni–neutroni fun nukleu je aba Dmitry Ivanenko ni 1932. Kìkì gbogbo ìkórajọ atomu lo wa ni inu nukleu ayafi die elektroni ayipo.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |