Nọ́mbà adọ́gba àti aṣẹ́kù
Ninu Imo mathematiki, gbogbo nọ́mbà odidi le je nomba adogba (even number) tabi nomba aseku (odd number) lona yi: ti o ba je odidi nomba ni opolopo meji, nomba na je nomba adogba bibeko yio je nomba aseku. Fun apere 4, 0, 8, 16 je nomba adogba bee si ni 1, 3, 7, 9, 11 je nomba aseku.
Akojopo awon nomba adogba se ko bayi:
- Adọ́gba = 2Z = {..., −6, −4, −2, 0, 2, 4, 6, ...}.
Akojopo awon nomba toseku se ko bayi:
- Aṣẹ́kù = 2Z + 1 = {..., −5, −3, −1, 1, 3, 5, ...}.
Isirosise pelu awon nomba adogba ati nomba aseku
àtúnṣe- adogba ± adogba = adogba
- adogba ± aseku = aseku
- aseku ± aseku = adogba
adogba * adogba = adogba
adogba * aseku = adogba
aseku * aseku = aseku
Ti a ba sepinpin odidi nomba ki se dandan pe yio fun wa ni nomba odidi pada. Fun apere ti a ba sepinpin 1 pelu 4, esi re yio je 1/4 ti ki se nomba adogba tabi nomba aseku nitoripe awon nọ́mbà odidi nikan ni won le je adogba tabi aseku. Sugbon ti ipin ba je odidi nomba, yio je adogba ti afi ti nomba ti a pin (dividend) ni opolopo iye (factor) meji ju nomba ti a fi pin (divisor) lo.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |