NECOM House
NECOM House (tí a mọ̀ sí NITEL Tower tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, tí ó sì fìgbà kan jẹ́ NET Building) jẹ́ ilé alájà-púpọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Wọ́n parí kihkọ́ ilé alájà-púpọ̀ náà ní ọdún 1979, ó sì jé olú-ilé NITEL. Kọnkéré ni wọ́n fi kọ́ ilé náà. Ó sì jé ilé tó ga jù lọ ní apá ìwọ̀-oòrùn ilè Africa lásìkò tí wọ́n kọ.
NECOM House | |
---|---|
NECOM Building | |
Building | |
Type | Commercial[1] |
Location | Marina, Lagos Island, Lagos, Lagos State, Nigeria |
Coordinates | 6°26′46″N 3°23′51″E / 6.4462161°N 3.3975961°ECoordinates: 6°26′46″N 3°23′51″E / 6.4462161°N 3.3975961°E |
Construction | |
Floor count | 32[1] |
Main contractor | Costain Group |
Design team | |
Architect | Nickson Borys & Partners |
Structural engineer | Oscar Faber & Partners in association with Obi Obembe & Associates |
Ijàmbá iná
àtúnṣeIlé Necom ti ní ijàm̀bá iná lẹ́ẹ̀mejì, láti ìgbà tí wọ́n ti kọ́ ọ. Àkọ́kọ́ ní ọdún 1983[2] èyí sì fa ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìsòfò dúkìá, èkejì sì wáyé ní ọdún 2015 tí ó kan orí-àjà ilé náà.
Àwòrán
àtúnṣeÀwọn ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Àdàkọ:Skyscraperpage
- ↑ Cowell, A. (13 February 1983). "A skyscaper [sic] fire in Lagos causes pangs of conscience". The New York Times.