Nadege Uwamwezi
Nadege Uwamwezi (tí wọ́n bí ní ọdún 1993) jẹ́ òṣèrébìnrin àti akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè Rùwándà. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òṣèré tẹlifíṣọ̀nù tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní orílẹ̀-èdè Rùwándà. Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bi Nana nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ City Maid.[1] Ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi aṣàpẹẹrẹ ẹ̀ṣọ́ aṣọ.
Nadege Uwamwezi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Nadege Uwamwezi 1993 (ọmọ ọdún 31–32) |
Orílẹ̀-èdè | Rwandan |
Orúkọ míràn | Queen Nadege |
Iṣẹ́ | Actor, singer, fashion designer |
Ìgbà iṣẹ́ | 2014–present |
Àwọn ọmọ | Ganza Benny Lucky |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Acting can earn you a decent life, says actress Uwamwezi". newtimes. Retrieved 14 October 2020.