Nadwatul Musannifeen
Àdàkọ:Use Indian English Àdàkọ:Infobox publisher
Ilé-ìwé Nadwatul Musannifeen (English: Council of Writers) jẹ́ gbọ̀ngán a ṣèwádìí àti ilé aṣètẹ̀jáde-ìwé ní Delhi. Àwọn ọ̀mọ̀wé Ọ̀gbẹ́ni Atiqur Rahman Usmani, Hamid al-Ansari Ghazi, Hifzur Rahman Seoharwi àti Saeed Ahmad Akbarabadi ni wọn dìjọ dá a sílẹ̀ lọ́dún 1938.
Ìtàn
àtúnṣeÀwọn ọ̀mọ̀wé Atiqur Rahman Usmani, Hamid al-Ansari Ghazi, Hifzur Rahman Seoharwi àti Saeed Ahmad Akbarabadi ni wọ́n dá Nadwatul Musannifeen sílẹ̀ lọ́dún 1938.[1] Ní ìbẹ̀rẹ̀, wọn dá ilé-ìwé yìí sílẹ̀ ní ìlú Karol Bagh, ṣùgbọ́n ilé-ìwé náà pàdánù lọ́pọ̀lọpọ̀ lásìkò rògbòdìyàn tó ṣẹlẹ̀ lọ́dún 1947. Lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ Partition of India, Ọ̀gbẹ́ni Atiqur Rahman Usmani gbé ilé-ẹ̀kọ́ náà lọ sí ìtòsì Jama Masjid, Delhi post the Partition of India.[2]
Ilé-ẹ̀kọ́ náà ti ṣe atẹ̀jáde ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé lórí ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn, àṣà, ìtàn àti ìmọ̀ Ọlọ́run.[3] Ilé - ẹ̀kọ́ náà ni ó ṣe atẹ̀jáde ìwé-ìròyìn Burhan, èyí ìwé-ìròyìn olóṣooṣù tí gbogbo ènìyàn gbà pé ó jẹ́ ìwé-ìròyìn Islamiyat tí ó dára jù lọ lẹ́yìn Al-Ma'ārif ti Shibli Academy.[4]
Àwọn akẹgbẹ́
àtúnṣeÀwọn ìwé
àtúnṣeNadwatul Musannifeen ti ṣe atẹ̀jáde ìwé tí ó ju 250, lára rẹ̀ ni Official Letters of Abu Bakr, Official Letters of Umar Farooq, Official Letters of Usman Ghani, Economic Analysis of Orthodox Caliphate, Ancient India in Arabic Literature, New Light on Indian History - from an Arabic manuscript, A statesman of the First Century àti History of Ridda tí Ọ̀gbẹ́ni Khurshid Ahmad Fariq, tí ó jẹ́ olórí àwọn Ọ̀jọ̀gbọ́n ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ èdè Arabic ní Delhi University ṣe àtòjọ rẹ̀.[5]
Ipa
àtúnṣeNí Jamia Millia Islamia, Ọ̀gbẹ́ni Abdul Waris Khan kọ ìwé ìwádìí ìgboyè ọ̀mọ̀wé tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ Islāmi Uloom mai Nadwatul Musannifeen ki Khidmāt: Ek mutāla, (Àdàkọ:Translation).[6]
Ìtàkùn Ìtọ́kasí ayélujára ìta
àtúnṣe- Nadwatul Musannifeen, Delhi in Encyclopaedia of India.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Nayab Hasan Qasmi. Darul Uloom Deoband Ka Sahafati ManzarNama. Idara Tehqeeq-e-Islami, Deoband. pp. 176, 198.
- ↑ Meerthi, Zayn al-Abidin Sajjad. "Mufti Saheb Ki Zindagi Ke Chand Goshey". In Mehdi, Jameel (in Urdu). Mufakkir-e-Millat Number, Burhan (November 1987 ed.). Delhi: Nadwatul Musannifeen. p. 46.
- ↑ Paul Jackson (1988). The Muslims of India: Beliefs and Practices. Delhi: Islamic Studies Association. p. 247. https://books.google.com/books?id=JbrXAAAAMAAJ&q=Nadwatul%20Musannifin. Retrieved 3 January 2021.
- ↑ Sajjad Zaheer (2006). The Light, A History of the Movement for Progressive Literature in the Indo-Pakistan Subcontinent: a Translation of Roshnai. Oxford University Press. p. 233.
- ↑ "Educationists mourn the death of Prof Fariq". The Milli Gazette. https://www.milligazette.com/Archives/01122001/16.htm.
- ↑ Abdul Waris Khan. "Preface By Shees Ismail Azmi". Islāmi Uloom mai Nadwatul Musannifeen ki Khidmāt: Ek mutāla. New Delhi: Islamic Book Foundation. p. 7. https://www.rekhta.org/ebooks/islami-uloom-mein-nadwat-ul-musannifin-ki-khidmaat-ek-mutala-abdul-waris-khan-ebooks. Retrieved 5 January 2021.