Nahzeem Olúfẹ́mi Mímìkò
Nahzeem Olúfẹ́mi Mímìkò tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kíní oṣù Karùn ún ọdún 1960, jẹ́ onímọ̀ nípa ètò ẹ̀kọ́ àti alákòóso àgbà tẹ́lẹ̀ rí ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì Adékúnlé Ajáṣin,[1] tí ó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ ti Ìpínlẹ̀ Òndó ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ilé-ẹ̀kọ́ àgbà tí àjọ tí United State Transparency International Standard (USTIS) sọ wípé ó wà lára àwọn ilé-ẹ̀kọ́ tó peregedé jùlọ ní ọdún 2014, lásìkò ìṣàkóso Fẹmi Mímìkò.[2] Olúfẹ́mi Mímìkò nìkan ni ó jẹ́ alákòóso àgbà ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì tí wọ́n yàn lọ síbi ìjíròrò àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó wáyé lásìkò ìṣàkòso Ààrẹ Goodluck Ebele Jonathan ní ọdún 2014.[3] Ó gbs ipò àṣẹ alákòóso àgbà ilé-ẹ̀kọ́ Adékúnlé Ajáṣin ní oṣù Kíní ọdún 2010. Ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ àjọ African and African-American Studies Associate, at Harvard University, Cambridge, MA, USA. [4]
Nahzeem Olufemi Mimiko | |
---|---|
Vice Chancellor of Adekunle Ajasin University | |
In office 4 January 2010 – 4 January 2015 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1 May 1960 Ondo State, Nigeria |
Àwọn Ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ No alternative to democracy – Prof Mimiko, Nigeria: Vanguard News Paper, 2010, retrieved 2014-08-03
- ↑ US agency ranks AAUA best varsity [sic] in Nigeria, Nigeria: Tribune News Paper, 2014, archived from the original on 2014-08-11, retrieved 2014-08-03 Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Prof. Femi Mimiko: The only VC delegate, Nigeria: The punch News paper, 2014, archived from the original on 2014-08-08, retrieved 2014-08-04 Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Adekunle Ajasin university Vice Chancellor Mimiko caves to pressure and reinstates ASUU leader and Members, Nigeria: Sahara Reporters, 2014, retrieved 2014-08-03